You Are Worthy

by Tope Alabi

ti:01 You Are Worthy] You are worthy You are worthy You are worthy Of my praise You are worthy You are worthy You are worthy Of my praise Eleburuu ike o O ranmo nise faya ti o Aran ni bani lo o You are worthy Oba to gba mi la o Olowo ino o Iwo nikan logo ye o You are worthy You are worthy You are worthy You are worthy Of my praise Baba awon baba Lion of the tribe of Judea King in his majesty Ruler of the universe I tremble at your feet Lion of the tribe of Judea King in his majesty Ruler of the universe Worthy of my worship Iwo ton joba lori gbogbo aye You are worthy Iso aye iso emi eda gbogbo You are worthy Olori angeli olori orun You are worthy Iwo ton dari aye ati orun po Of my praise Iwo to da ohn ko diju ri You are worthy Gbongboki ooro to aye ati orun You are worthy Ipa nla gbogbo aye You are worthy Oke ati ile emi eniyan Of my praise Gbogbo ola Olola to ga julo Oloro to po julo Ologo to ga ju You are worthy Oba toju gbogbo oba lo Ijoba nibi gbogbo lori aye Nisale ile Alayi ni pekun You are worthy Baba meta lokan You are worthy Ajulo ton nbe nibi gbogbo eda eniyan You are worthy Ara orun won ri Of my praise Ara aye won ri o ti isale won mo o You are worthy Amo daju eda gbogbo You are worthy Ninu emi ati ara lati mo o You are worthy Lafi ripe iwo nikan lope ye Of my praise Ofi orun nikan se kiki da wura O da orun ati aye pelu ara oto Ebo mi ajisa aji tola Mo gbe osuba fun ogo rabale Ibere ogo arin ogo Olu kangun ogo igbeyin ogo Eni ti gbogbo aye yio pada wa bo Kabiyesi o Araye koba ni kabiyesi Woni kade pe lori ki bat ape lese o Iwo nikan ni kabiyesi Ta o gbodo sope ki ade pe lori fun A o gbodo pe ki bat ape lese Lai lai Se ade ta o mogba to de sori e Se bata ta o mogba to wo ese re Ti angeli gan o mo Gbogbo awon torun njuba Iwo nikan ni won bo o Kilo wa semi se aye mi Ti un oni ma bo o Gba ogo ati ola Gba ogo ati iyin Iwo nikan lo to si You alone at worthy lord Gba ogo ati ola Gba ogo ati iyin Iwo nikan lo to si Agadagodo emi gbogbo eniyan Gba ogo ati ola Gba ogo ati iyin Iwo nikan lo to si Gba ogo ati ola Gba ogo ati iyin Iwo nikan lo to si Gba ogo ati ola Gba ogo ati iyin Iwo nikan lo to si Eni to fi emi e rubo fun emi Gba ogo ati ola Gba ogo ati iyin Iwo nikan lo to si Tani nba tun fi fun Gba gbogbo ogo oni ba enikeni pin Iwo nikan lo tosi You are worthy You are worthy You are worthy Of my praise You are worthy You are worthy You are worthy Of my praise You are worthy You are worthy You are worthy Of my praise Iwo nikan lo worthy Mo gbe ola fun o Mo fiyin fun o Mo f'ogo fun o Mo dara po mo awon torun lati sowipe Ose Tori o worthy o