Orun Oun Aye

by Tope Alabi

un oun aye kun fun ogo re Orun oun aye kun fun ogo re Egbegberun awon irawo kede ogo re Kinni o waa se mi ti n o ni le maa juba re o e Orun oun aye kun fun ogo re Orun oun aye kun fun ogo re Egbegberun awon irawo kede ogo re Kinni o waa se mi ti n o ni le maa juba re o e Didara orun oun so togo re o olorun Ewa re to yi aye ka n so togo re bo ti po to Gbogbo eda eranko at'ewebe n yin o o Ise owo re gbogbo lo n keyin le won yin o o baba Orun oun aye kun fun ogo re Orun oun aye kun fun ogo re Egbegberun awon irawo kede ogo re Kinni o waa se mi ti n o ni le maa juba re o e Ola lo wo laso ogo lo fi pa kada orun Ika ese re o n han l'ori apata Esin re n fogo yan l'ori awo okun o olola nla Kini o waa se mi ti n o jokeleyo Ti n o ni le juba re oba Orun oun aye kun fun ogo re Orun oun aye kun fun ogo re Egbegberun awon irawo kede ogo re Kinni o waa se mi ti n o ni le maa juba re o e Gbogbo emi inu mi o n yin o yato olorun mi Iwo to mu la ina koja to fi mumi goke Kini mba fi fun o Kini mo tosi ninu oreofe ti mo rigba lodo re Oba ye mida majemu lati nu'mole Oro ye ye osise Oba ti ki n dale oro ore Iwariri ni n o fi juba re Orun oun aye kun fun ogo re Orun oun aye kun fun ogo re Egbegberun awon irawo kede ogo re Kinni o waa se mi ti n o ni le maa juba re o e Orun oun aye kun fun ogo re Orun oun aye kun fun ogo re Egbegberun awon irawo kede ogo re Kinni o waa se mi ti n o ni le maa juba re o e