Olorun Ni Yio Maje

by Tope Alabi

ti:03 Olorun Ni Yio Maje] Olorun ni yio maje Olorun ni yio maje Lano loni lola o Titi de aye raye Olorun ni yio maje Olorun ni yio maje Olorun ni yio maje Lano loni lola o Titi de aye raye Olorun ni yio maje Alagbara ni kose segun o Ipa nla kode le ku o Ayileyipada toni aye ni ikawo Emi se iba oluda orun o Emi se iba oluda orun Olorun ni yio maje Akoko nda olu da aye Olorun ni yio maje Pata pata pira ogo nibi to pari si Lano loni lola o Titi de aye raye Olorun ni yio maje Ayile tun wa oti wa koto da orun Tele ri ni ati titi lo ni Eni nigba ti koni ibere beni ko lopin Mo juba akoda aye o Pata pata ogo Olorun ni yio maje Eni l'ade to ti d'ade kato da aye Olorun ni yio maje Eni l'ade to ti d'ade kato da orun Lano loni lola o Titi de aye raye Olorun ni yio maje Kosi eni to da nigba to tin joba o A o to owo eda kan mu ade ori e Akobi orun o olusaju aye de Jehovah emi se iba Ogangan oju awon agbagba merin Olorun ni yio maje Iriju oju awon angeli ojojumo Olorun ni yio maje Iba eni tawon torun se ti won o dake Kosi ari yan jiyan lorigun merin orun ati aye Koni se ayi je olorun mo Olorun ni yio maje Iwo nikan ni oma je olorun Olorun ni yio maje Oti da lorun koto da orun rara Kosi ari yan jiyan lorigun merin orun ati aye Koni se ayi je olorun mo Olorun ni yio maje Emi se iba koto kan oro ashiri aye Olorun ni yio maje Ashiri aye pelu orun owo re lowa Lano loni lola o Titi de aye raye Olorun ni yio maje