Mori Yanu

by Tope Alabi

e e e e e e ah ah ahaahaha o o oooooooo Mori yanu eee iyanu mori yanu ehe iyanu E e e e e e e ah ah ahaahaha o o oooooooo Mori yanu eee iyanu mori yanu ehe iyanu Ba won kan ba ku se ni gba kan laiye won To ba d'lowo won so wi pe iyanu ni Bi elomiran ba ya agan ri to ba wa dolomo e e Won so wi pe iyanu loto iyanu ni Bo ko ba dun to run geje te nikankan o f'ara pa Eni ori re pen i ile ta ro pin t'olorun wa gbe ga Tabi eniti o gbo ojo iku to palemo ti o pada wa ku mo Gbogbo re lo je iyanu e iyanu E e e e e e e ah ah ahaahaha o o oooooooo Mori yanu eee iyanu mori yanu aaa iyanu ni Iyanu to se kenken oka mi laya titi Ilu kekere kan wa won o toro je beeni won o la won o se agbe Ara birin kan wa to ji se fun pe o ma bi iyanu Eda o leru pe iyanu le ti be wa o Okuku sele be a bi mo na bi o ti le jo iyanu Sugbon bi o ti jo iyanu to oba ilu kan un wa kiri Oun wa lati pa tori e o pa opolopo omo Egbo kini ijoloju ki lo fe f'omo talaka se B'aiye ti ri niyen eni ma ga oju a ri to E e e e e e e ah ah ahaahaha o o oooooooo Mori yanu eee iyanu mori yanu ehe iyanu O da ba iyanu Ise iyanu akoko iyanu E kana ti galilee iyanu Oro ninu tempili iyanu Oku omo jayiru iyanu Batholomeau afoju ko iyanu O da ti pada fun alati iyanu Orin lori omi akayika tan nise iyanu re Iyanu to ga to jo emi loju ju o Won da baraba sile amu alaiyese o ma se o Ikan e ba kan eya ekan rere ata ti o e fi boju Ponripori e lori igi agbelebu lo so pe o tan Ah abi e o ri iyanu Aro ni lara yeye iyanu Iyanu e yi gangan iyanu A be ni lowo ekun ti iyanu Iyanu wo lo to eyi ka bi eniyan tori ese araiye Iyanu wo lo to eyi o ki a somo nu tori elese paraku Ibaje awa loun se a le se e je a bira wa Ka ma de na pelu ako ise oba rani iyanu ni eeeee E e e e e e e ah ah ahaahaha o o oooooooo Mori yanu eee iyanu mori yanu ehe iyanu Ko si ebo ko si etutu to ma koja eni fi emi re lele Ko tun si ife atata kan to dabi ife oluwa Abi eni wa si aiye lati wa kese aiye gbogbo lo Ko tun si iyanu mi ran mo o eyi ni iyanu Oku a si sin o ji ja kadi ni sare O gba kokoro lowo iku Ogbe iku min ni isegun Iku oro re da o Isa oku isegun re da o Ora iye araye nip o oku O gin de lojo keta (o ma gi o) O gin de tiye tiye lo gin de Si ile aiyeraye gbogbo eni to yan iye ko ka lo O gin de tiye tiye lo gin de Si ile aiyeraye gbogbo eni to yan iye ko ka lo O gin de tiye tiye lo gin de Si ile aiyeraye gbogbo eni to yan iye ko ka lo O gin de tiye tiye lo gin de Si ile aiyeraye gbogbo eni to yan iye ko ka lo Ita iyanu ti ife nla le yi o Lati odo baba eleduwa baba wa Eni sanu gbogbo wa to fi omo re ra araiye pada Agba iyanu to bi iyanu to eniyan un ri Ita iyanu ti ife nla le yi o Lati odo aseda eleduwa baba wa Eni fi ife da wa ti o fe ka pa run Agba iyanu to bi iyanu to eniyan un ri Ita iyanu ti ife nla le yi o Lati owo ife eleduwa baba wa Eni gba wa sile to fi omo kan soso saw o tan ese wa Agba iyanu to bi iyanu to eniyan un ri