Ki I Koni

by Tope Alabi

ebi le koni,kara koni kegbon koni,kaburo salo iwonikan lemimo o tikii koni o ebi le koni ,kara koni kegbon koni kaburo tun salo iwo nikan lemi mo o ti ki i koni o o kii koni o oo koni o o kii koni ooo ko yan o kii koni ooo koni o kii koni o thank you lord Jesus toba JE pe o lowa ni asiri wa o titu gbogbo ohun ta n bo titi ni o wa ohun gan mo pe packaging la n fisi sugbon packaging ti wa ko lo je ko fine packaging ti e loje ko make sense to ba ele shi packaging yen ah, okere de gba alate o kawo leri niyen o olorun tikii ko eyan o Baba le koni ki ya koni kegbon koni kaburo salo iwo nikan lemi mo oo ti kii koni oooo o kii koni ooo,koni oo okii koni oo Jesu I koni o iwo nikan lemi mo ti kii koni ooo koni ooo koni oo (JE n gbo e) koni ooo koni o eeeeee koni ooo koni oo ti kii koni o o ki koni ooo koni o o kii koni ooo koni o o kii koni o koni o o ki koni ooo koni oo to ba JE bi aye ti n gbani segbe ni ti won n ko yan ni lo ma shey nko yan ni eni e ko ti po nle gan o kii ko yan ni o ki ko yan ,o je ko awon ti e oni majemu ayo ti kii da majemu agbe o ga loni ashey o loba kii sheep ati Dade fun o sugbon afope wa de o lade kii shepe a to firukere le o lowo sugbon a fi ope wa firukere le o lowo kishepe ato bee tale fi ewe akoko de