Ise Owo Re

by Tope Alabi

Igba to mu omo Israeli loko eru Ao le sopee O mo won akan okun pupa Igba ti Danieli rufin Oba lojo si O ku ku mo pe Iho kiniun ni Won o sooosii Omo eberu metta ko Won o fori bale oo Oo shaimo won a ju won Si inu ina o Iwo to o pin Okun niya Iwo to pa eyin Kiniun mo Iwo naa lo sikerin Ninu ina ileru aaa Eru re maa to ba ooo Olorun ogooo Eru re nba mi oooo Ise owo re nba mi leru nIse owo re nba mi leru ooo Oun to mo Iwo gangan la momo tan olodumare nIse owo re nba mi leru O nba mi leru Igba ti lasaru saisan Won ranse si o o Ao le pe oomo pe Yi o la iku lo ni Igba ti Abrahamu fe sarah Ni wundia Okuku mo pe Oo fojo Igbo won dara ire Igba to ni ki abrahamu Fi isaaki rubo fun o oo Sebi iwo naa lo fi Agbo eran dipo omo fun Iwo to ji oju lasaru Iwo to fomo da arugbo lola Iwo to fi igboran Fi agbo eran dipo Omooo Eru re to ba oo Olorun Ogo oo Eru re nba emi oooo Ise owo re nba mi leru nIse owo re nba mi leru ooooo Iwo to ni iku ati iye O mora e awa ni o ye eee Oluda Olubi Awogba arun ma gbeje Ayiwo ojo pada eeee Oun to wun o loun se Igba ti josefu lala Ko ba ti roo Ao le pe oomo pe Awon egbon re yio seke ta Igba toba laala eru To n wa eni ti o roo Okuku mo pe elewon josefu Ni yio tu fun oba Iwo naa lomo Pe josefu Aa pada wa bo gbogbo ebi e Emi o ri oun to seyin re ri Aditu oba ogo O fi Iran ogo han josefu O tun mu oba laala aditu Iwo to fi elewon se edidiyan Eru re to ba oooo Ijinle nla ni o aaaaa Ise owo re nba mi leru Ise owo re nba mi leru Iwo lo fope damu ologbon O fi alailagbara damu alagbara ooo A fori sofa nitori ogo Moyanmoyan ni o Too moo yan saye to yan to yanju Olorun nla O n ba mi leru ooo O ran isiah to Ezekiah lo Oyeku ni o O gbeyin boro yo O gba satani laye ni Ile jobu Okuku mo pe ilopo loofi di Bo ti je gaan niyen Asiri lojeee Bo ti ri gaan niyen Iwo ni ijinle oooo O gbona eburu fa kayefi eee O buse gada soro Ana di bami koju o to mo o Eni aye sope ko le se tooo tele O wa ko ile alaruru ni igbeyin Eni ore po fun tori ise ni ijosi oo O pada wa di olota o Nitori oro Iwo to mo opin lati ibere Eru re nba mi ooo Eni ti o beru re Oun to da ju sobia lo aaa o nba ni leru nOlorun amomotan Ko si amoju loro re ooo Iwo ganga ni yeee Olusaju aye de Oro to wa Ka to maa soro nIjinle to fi ijinle bora Ise owo re n ba mi leru Kayefi nla to n ka ni laya Ise owo re n ba mi leru Awari olorun ogo Ise owo re nba mi leru Awamaridi onise nla Ise owo re nba mi leru Ise owo re n ba mi ooo Ise owo re nba mi ooo Ise owo re nba mi leru nO bami leru ooo Eleru niwa ni o Eleru nise ni o Iwo leleru loro Eleru lero oo Oloro to po Aye owo re Orun ikawo Kabiesi ooo On ba mi leru ooo