Halleluyah

by Tope Alabi

ti:02 Halleluyah] Hallelujah Ni wun o ma ko Hallelujah Si iwo olorun mi Orin hallelujah ni wun o ba awon torun ko o Hallelujah Ni wun o ma ko Hallelujah Si iwo olorun mi Orin hallelujah ni wun o ba awon torun ko o Oju orun fun dede Awo sanmo nipele nipele Eru lofi ko aye o kun fun ajara Eda o yanbo awo iwo lo dawa lawo ototo Mo korin hallelujah si iwo ti awon torun nbo Hallelujah Ni wun o ma ko Hallelujah Si iwo olorun mi Orin hallelujah ni wun o ba awon torun ko o Mimo mimo ni won nke Awon t'eda orun Angeli lo wo won nfojojo fori bale o Agbagba nke mimo solu dande aye gbogbo Hallelujah soni ite ogo aditu Gbogboro owo to no aye ja lati inu orun wa Ki korin won o dake ri si olorun awon omo ogun Hallelujah Ni wun o ma ko Hallelujah Si iwo olorun mi Orin hallelujah ni wun o ba awon torun ko o Hallelujah Ni wun o ma ko Hallelujah Si iwo olorun mi Orin hallelujah ni wun o ba awon torun ko o Hallelujah ni won ko Won segun aye Kosi daru dapo oun gbogbo nlo leto leto Ebi ko pa won ri Be lara ko ni won ri Kida ayo ekun rera alafia ni ite ogo Awa ta le ke hallelujah ninu aye Awa lafi orin isegun se a logo A o jeri ota won o deni itemole pata Orin hallelujah la ofi ba jesu joba Awa ta gba la Hallelujah Ni wun o ma ko Hallelujah Si iwo olorun mi Orin hallelujah ni wun o ba awon torun ko o Hallelujah Ni wun o ma ko Hallelujah Si iwo olorun mi Orin hallelujah ni wun o ba awon torun ko o Si olorun lailai hallelujah o Hallelujah Si eni to nbe lori ite hallelujah o Hallelujah o Si eni to logo pata pira ibere ati opin Si eni to da aye ati orun to shaju de pada gbeyin o Hallelujah o ooo Hallelujah ooo lorin mi Hallelujah ooo lorin mi Lorin mi Lorin mi Yio je lojo Hallelujah Yio ma je Hallelujah Losan lowuro loru Hallelujah Hallelujah Hallelujah