Aye

by Tope Alabi

Ohun ti eda ma je laye inu e lo wa oo Ibi ti eda ma de laye inu e lo wa oo Eda o le mono ko pon ko gbe ladugbo dani Ero to n lo sodo ni o ponmi bo wa le Toju inu ee Toju inu e Toju inu e ooo Toju ero re ooo Ero gbogbo ero gbogbo ke gbo oo ke gba Toju inu e toju okan re o toju ero re oX2 Akaba ti eda ma n gun laye inu e lero wa oo Eda ti o wo aso alari inu e dan Alainiran to n Ki Oba ni loro kole joye layilayi Tori eni ba moyi wura la mi n ta fun Toju inu ee Toju inu e Toju inu e ooo Toju ero re ooo Ero gbogbo ero gbogbo ke gbo oo ke gba Toju inu e toju okan re oo Toju ero re X2 Awujo awon ton banri awa o lati inu e Eyan meji ko le rin papo lalai se pe won mowo ara won Obun ti o bo mi osun kan ra to n wa pe alagona ni werey o ye ko mo p' ologini ri omo ekun ni Toju inu ee Toju inu e Toju inu e ooo Toju ero re ooo Ero gbogbo ero gbogbo ke gbo oo ke gba Toju inu e toju okan re Ero ti eda n ro laye lo n gbe won rinrin ajo ototo bokan da ba buru laye aye e shamalamala agbonri ri ewa bo n lono ijapan wa koto sona fun sere taja f'ogun odun sa fanda leshin fin yan Koto ti japa wo sile na li o ni je ko lo oo Odun ti kiniun ti peran je seni Aja sha yan Ma sho oooo ero okan re Be positive all the time bo ti wun ko ri Ero inu dori ayanmo kodo keya sho oo Opo ohun ti eda n ro oun bawon ri irin ajo Eni ro rere o ti se o Eyan to n ro ika o ti se Opo ohun ti an ri laye eda ero won ni Toju inu e toju okan re o pelu ero re Toju inu ee Toju inu e Toju inu e ooo Toju ero re ooo Ero gbogbo ero gbogbo ke gbo oo ke gba Toju inu e toju okan re o toju ero reX2