Agbelebu

by Tope Alabi

a eda to l'orun da (awa eda) Aiye oto ototo lawa (aiye oto) Oni kaluku lo yan ayamo (beeni) Aiye agbelebu lawa O o o o o o hun o o o eh eh Agbelebu oooo Ede to wa si ile aiye Ka to le lo a o sukun o (a o sukun o) Aiye agbelebu lawa Ta ba bi omo tuntun jojolo o Tibi tomo ni yo kowo ru bo w'aiye A kehinde omo aladarin omo Ibi sha loruko re je Ibi ati ri ibi eda ole so Igba ibi defun eda omo l'aiye Eyi wa se ari daju wope Eda to w'aiye pelu ogun na Aseda to da wa O o o oo o o o o eh eh Agbelebu ooo agbelebu o ni gun merin Eda to wa si ile aiye Ka to le lo a o sukun o Aiye agbelbu lawa Ba ti wa aiye pelu ibi Be l'aiye pelu ayamo Apoti ogo o ba wa w'aiye Kokoro to si on'be ninu adanwo Bi a ba sin ibi a kin sin ogo Ogo farasin si aiye eda gbogbo Ka to le lo a o segun na Kokoro ogun ayirin a gbodo wa (a o ti se wa) Awa eda to l'orun da (a de fi kawa o) Aiye oto ototo lawa (ka to le si apoti o) Oni kaluku lo yan ayamo (oni kaluku lo yan ayanmo) Aiye agbelebu lawa O o o o o o huh huho o Agbelebu oooo Ede to wa si ile aiye Ka to le lo a o sukun o (a o sukun o) Aiye agbelebu lawa Sa ba bi ni agbelebu je A ma ja si re fun awon to ba le gbe Elejo wewe kin lle gbe agbelebu Won ma b'ogun aiye won ro jo Tasiko ba koja lo won o ni fura Jobu koju ida wo l'aiye Kaka ko fi ejo se olorun O gbe agbelebu re layi wo eyin Igba ti isoro tan e wa wo ara Ara nla ti olorun fi da O o o oo o o o oooo Agbelebu oooo Ede to wasi ile aiye Ka to le lo a o sukun o Aiye agbelebu lawaa Ala yi nibe re so agbelebu deru Won so ogun igba die di oba won Won wa foribale fun Isoro basi joba laiye eda to Ole se be peni ron se dojo ogbo Iru wo kin le ro ire mo ra won Ko da won tun so de bi olorun Won ma gongo ori imu adani waiye Ti won fi owo jun Ika a kun inu won wo o ni le bon i re yo Ise woyin lo mu won gbaiye Be eniti ko gbo ogo wo aiye yi rara oooooo Awa eda to l'orun da Aiye oto ototo lawa Oni kaluku lo yan ayamo Aiye agbelebu lawa O o o o o o ooo Agbelebu oooo Ede to wa si ile aiye Ka to le lo a o sukun o Aiye agbelebu lawa Ayi le gbadura Ayi gboran pupuru ese ati ikan ju okan Omu ki ota lo asiko agbelebu Lati gba emi lenu elomiran Awon omo isreali so irin ajo ogoji ogo Dogoji odun mo ra won lowo Serin afowo fa ati ayi ni suru Ati ayi ka abgelebu kun ebo gbigbe Ko je ki elomiran ko mo ona ati rin De bi ogo ogo re Eriri aiye kole tin i pa e jowo Inshe ni o fogbon ko eda l'aiye Se wa ri agidi ogbon agbo ju eniyan A mu kelomiran ma wo apoti ogo won lokankan Layi ni le debe Olorun fi ileileri won mose Sugbon ko de be rara Olorun kin da majemu to ba enikeni da Beeni labe akoso boti wun kori o Olorun je o lododo Ko ni se dalebi lonakanno Oooooooo oooooooooo Abgelebu ooooo Eda to wa sile aiye Ko to le yo a sukun Aiye agbelebu lawa Eyan to yo se lokan kole kun Won kan ju won gbe se ni meji meji Won fe fo lona abgelebu ti won Se l'aiye won gbojikan fun isira satani Amo ona to wo ebo Aiyisan a pa ni ku saiye Paya yi layi wo okan Iku ayi to jo wa lo bi rere Ola ti ipanju da won niyen Layi mo pe ko si adanwo ti enikan o ri Awon to ka si won o ni iriri Eniti ko ni e iriri ko le ni eri Ma je ki agbelebusoe di alayi gbagbo Nishe lo ye ko fun o lagabra Nitori o fi asiri ikoko wonni Ati ba o se to laiye ba o se fe to laiye Ani bi a o se to laiye ba o se re lo to laiye Oro gbogbo odowo re aseda (o dowo re aseda) Ayi fi ka be olorun ko gbo Agbelebu dandan agbelejika Ka mo leru ka ya tete gbe Oro gbogbo o dowo re aseda Ayi fi ka be olorun ko gbo Agbelebu dandan agbelejika Ka mo leru ka ya tete gbe Eniti ol e sa ko so okan re Ko ni le gbe agbelebu de ibi ogo Ko to de ni afokan tan a o ye o wo Irubo loje o ko nipe tan Olugbala nagbe to eri o Ko to gba ade ogo ojuboro ko Ona agbelebu ja si koto jasi bebele Bo tin huh be o ko ma gbadura Ma si ye meji ko ma ba se lasan Ma jowu ogo o logo layida Ko ma ba jiya lo silkeun ti fo Gbe gbe tele olugbala Oruke jesu lowo ile ogun Oruko jesu ile iso agabara Olododo sawo be o si ri iye Gbe agbelebu re o e bo re ni Fi igbagbo gbe o gba gbogbo e si ayo O fere debe na o da mi loju Ki lo mo to je agbalebu re Oun ko oun lo le je beere mole ko ya gbe (yara beere gbe) Agbelebu atete gbe atete debe Adani waiye fi adawo so ibi dire beeni beeni A ma gbe tie tegan tomije koyi biomo o Omo isreali gbe ti won pelu ekun kan ile ileri Ruth gbe agbelebu pelu ikoro ara e gbo o O kuku gbe tan o leri to po to ga o Iran ruthu lati bi jesu oluwa wa o Bori ba ti mo lo se un o fo olori Ologo nla irubo kenken Eleda n wo omo adamu ko te le fun To ba fun e saju o le ma mo lo oo Owo ban wi ile lo tan fun ni Abraham je ore olorun oju lasan ko Josefu o fi oju boro de po oja lamba Igbele nibi jabesi ko to se re re Ki estheri to di aya oba oti sin ilu ri o Ma reti eniti o rn o ti o ban gbe lowo Abgelebu da da gbe a jo so Juju l'aiye wa ki olorun to pe imole Ona agbelebu aji ju eru ni To ba mu ramu ramu ma ba wo yin o Ko si eniti o nigbe afi alayi ni ogo Gbe pelu igboya wato de be A mu ni pade pade pade A mu ni pade angeli a banise Awa eda to l'orun da Aiye oto ototo lawa Oni kaluku lo yan ayamo Aiye agbelebu lawa O o o o o o o o Agbelebu oooo Ede to wasi ile aiye Ka to le lo a o sukun o Aiye agbelebu lawa Lagbara baba o (lagbara baba o) Lagbara baba orun (loruko jesu) Awa yio de bi ogo lokan (lokankan) Ipin wa ko ni fo wa o (etewo adura) Kokoro ogo a ri gba Apoti ogo ma de be si Emi ni yio je ere ogo mi Orun o ni wo mi o ma gbe dele Eniti to lo ema wo eyin Eniti o simi e tese mo rin ema yi ti simi Eniti ti o ja jun segun oun lo simi Aiye de la raiye de lo ri re Lagabara baba oo lagabara baba orun Lagabara baba o lagbara baba orun Ogun rere sa ni ipin mi Emi ni yio je dogbo Lagbara baba o lagbara baba orun Ogun rere san i ipin mi Emi ni yio jere