Adake Dajo

by Tope Alabi

ake dajo adake dajo Oun lo mowa o Omi wo wa w'okan Oun gbogbo ti an'gbaiye se Oun lo da ojiji mo wa oo Ipinle se aiye wa o ati opin re Ori gbogbo koro Adake dajo adake dajo Oun lo mo wa o Omi wo wa w'okan Oun gbogbo ti angbaiye se Oun lo da ojiji mowa oo Ipinle se aiye wa o ati opin re Ori gbogbo koro Enti o da oju o Ko ni se alayi ri ran Olu to da eti o ko le sa gboran Ko si kor loju re Gbangba kedere lori wa Adake dajo Adake dajo Oun lo mo wa o Omi wo wa w'okan Oun gbogbo ti an'gbaiye se Oun lo da ojiji mowa oo Ipinle se aiye wa o ati opin re Ori gbogbo koro Ka ye se si ka ye peni esin Ka lo jawo pata A o le gan olorun pelu igbagbo oju Tori ko ni le gbawa A un fi ti pa gboran si ilan esin Ofin olorun wa da afi eyin O po dara loju iwa won o dokan Tegbin ti idoti o je ki adura opo onigbagbo o gba Ojiji ti eleda da mo wa o se afihan oun ikoko o A o ni le gba bo de fu olorun onitoun a wule tan ra re pa Olorun alopo dakun ma wo mi pa (olorun ma wo mi pa) Adake dajo Adake dajo Oun lo mo wa o Omi wo wa w'okan Oun gbogbo ti an'gbaiye se Oun lo da ojiji mo wa oo Ipinle se aiye wa o ati opin re Ori gbogbo koro Emo to wo ijo olorun ti wa ju reke Gbogbo aiye di iranse olorun Ati eni baba ran ati eni ebi le de Woli osan gangan iyen o bi rere Ori pepe di igbale egungun Ati alafose ati elepe Ogo ologo de kun tori wo se agbara Igba di be labe kola opo won Awon ti ogun ja ti won tori ki ogun le se to wo inu ijo wa Oma se ara kunlaso gba gi logun ton ku ogun Abi e o ri ijo ki jesu yio de ki ni yio da o Inje yio w aba igbagbo laiye Adake dajo Adake dajo Oun lo mo wa o Omi wowa wo okan Oun gbogbo ti an'gbaiye se Oun lo da ojiji mo wa oo Ipinle se aiye wa o ati opin re Ori gbogbo koro Eje ki a bi rawa lere Gbogbo iranse olorun pata Kini idahun si ibeere yi o Oro ijoba orun ti di iwasu igba ni lenu wa Ere wo loni so wo agba ni je ninu ise wa (e gbo) Ere wo erewo loluwa nje Afo wo le o ma n wo wa o Ko ma gbe ise mi la yi lere Kankan Kiloro kiloso nigbati a ba pe oruko omo eniyan To ba pe omo o won kiloruko re kilo o so Kiloro kiloso nigbati a ba pe oruko omo eniyan To ba pe omo won kilo ro kiloso To ba pe oruko won ni ijoba orun Ta pe won titi ti o kan e o Eniti o to ka si orun apadi Ati eyin to mo ona ile ologo Toba pe oruko ni ijoba orun to o ka mr sensor re kilo ro Kiloro kiloso nigbati a ba pe oruko omo eniyan To ba pe omo o won kiloruko re kilo o so Kiloro kiloso nigbati a ba pe oruko omo eniyan To ba pe omo won kilo ro kiloso Oni igbagbo kari mi ete eke Ka ti inu ijo jera wa lese dede Adura ati awe odi si anikeji Ife ikoko lori pepe si pepe E o ranti o da ogbon oju ogbon lo E o ba lako bi ibi lese ojiji Kiloro kiloso nigbati a ba pe oruko omo eniyan To ba pe omo o won kiloruko re kilo o so Ojo nla adajo aiye fere de Ayi wa pada idajo a wo Konikaluku lo ye ra e wo Ibi to ku si gbadura ko tun se Ko ma da di ki lo ro Ki enu ma ba di ayi le soro Kiloro kiloso nigbati a ba pe oruko omo eniyan To ba pe omo o won kilo ro kilo o so E e e e ee mo wi temi o ore ma diti Ko ma di ona orun mo ra re O tin fami han jesu oni pe de Eru ibi ton be loju re lo gbe kuro Ko ye tenu bo le soro Lo ro nu ko pa iwa da ka si toro fun anu Ka ju won ju se ka ju won fun olorun Ka le joba ka wa mo won Ise wa laiye yin i la ti wa ijoba olorun Leyin re ohun to ku ao fi fun wa Oun bo layi pe sa sa ro laye re Ise wa laiye yin i la ti wa ijoba olorun Leyin re ohun to ku ao fi fun wa Oun bo layi pe sa sa ro laye re Ise wa laiye yin i la ti wa ijoba olorun Leyin re ohun to ku ao fi fun wa Oun bo layi pe sa sa ro laye re