Abo Mi Kodara

by Tope Alabi

agbara aiye aiye a tan oo oo Eni loni e gbo awon ti o se ano wo si mo Igba loni gba lo bawo losi re, a be da su yo se san Olojo di e laye ma gba on akan kan Alagbara aiye aiye a tan oo oo Eni loni e gbo awon ti o se ano wo si mo Igba loni gba lo bawo losi re, a be da su yo se san Olojo di e laye ma gba on akan kan Ofe fe laiye asan ma je o wo e leje Igba o lo bi orere ofo mu sa bi oshey bi Ofada gbara o keya lomo Oti pa ida pani o gba ida ku o Alagbara aiye aiye a tan oo oo Eni loni e gbo awon ti o se ano wo si mo Igba loni gba lo bawo losi re, a be da su yo se san Olojo di e laye ma gba on akan kan Mo fe di mimo mo fe di olowo To ri e osun orun waju po moti ipako Eniti o jaiye jeniyan apadi lo je won Ni o je won mourn, ki esun ko se ore re titi Ko ni pada yan e je Alagbara aiye aiye a tan oo oo En loni e gbo awon ti o se ano wo si mo Igba loni gba lo bawo losi re, a be da su yo se san Olojo di e laye ma gba on akan kan Aseda to da wa kin kan ju Pele tu lo da aiye lo da orun Ohun lo fi pele se won lona ara Eni ba kan ju yo sanu ninu ise owo re o Ohun ami sare le kin tele ni de orun Ewo auye ke ro ni Alagbara aiye aiye a tan oo oo Eni loni e gbo awon ti o se ano wo si mo Igba loni gba lo bawo losi re, a be da su yo se san Olojo di e laye ma gba on akan kan Bi araiye ri o bi ero ano wo o, Shey ni won gbelu e Mo pe oloro ni o jinijini to fin mu eniyan Pelu eru igba to se toto koni enikan Eda aiye pata lo ni igba ti o lo Igba ti e mattan o di asiko olorun Ogolonto to le oba to ri gbajumo odaju Ko ni lo laiyi jiya ema gbagbe Edumare to iye na loni gun Eba je ki beere ki lagabara temi Oba je ki abeere ki agabara teri Ahon lagbara elomi ran wa Ton fi enu ba ikan je, alagbara Owo lagabara elo mi ran wa ton fi da ikan ru, alagbara Se inu lagabra tire to koro bi ijogbo Ti o ban binu si aniyan wa wo bi ko subu Ttabi koku, Alagabar Agbara ati sunmo eniyan bat i eni je La gbara elo mi, agbara Agbara e teriba lati jale, tabi lati seka Ese lagbara elomiran wa ton rin lati se bi Ipo lagbara elomi ton fin ni omo lakeji lara Ema je a gbagbe pe ile aiyema tan o Bi aiye se lon ni eniyan kuro Igba egberun onigba Igba igba onigba o Gbo gbo igba loni igba pata Asiko re lo serere, Bere ni ibikan kp pari e si bi kan o Eniti o ni eni dandan a to kuro o Arugbo se omidan ri, igba lon lo Ohun to ma tan, oma tan Ko ma ba aiye mi je Omo ti ama na to ma tan Ko ma baiye m je Ile ti ama ko ti a ma gbe ta ma ku Ko ni ma aiye mi jeoo Golu ti a ma nit i o pa mi Ko ma baiy mi je Okiki ti a ma ni ta ma ku Ko ma baiye mi je Buruji to ma tan to ma tan to ma tan Ko ni baiye mi je, olorun gba mi o Ipo ti ama de ti elomi ran ma joko si be Ko ma baiye mi je Ewa to ma ni tama ni Ti o pada di arugbo oo ko ma ba aiye mi je Ola ti a ma nit i a ma nit i a o tun fi si le Ko ma ba aiye mi je Ohun gbogbo lo ma tan lo ma tan Ka ma tan ara wa je