Wá Wọlé & Worshiṕ (Live)

by Sola Allyson

Eyin Oba ogo, On ni Olorun Yin fun 'se 'yanu ti o ti fihan O wa pelu awon ero mimo l'ona O si je imole won l'osan l'oru. E yin Angel 'didan, lu duru wura Ki gbogbo yin juba, t'e now oju re Ni gbogbo 'joba re, b'aye ti nyi lo Ise re y'o ma yin Ise re y'o ma yin Fi ibukun fun Oluwa okan mi Eyin Ni oluwa, Jehovah Eyin Ni oluwa Oba wa Eyin Ni Oluwa, Jehovah Eyin Ni Oluwa oba wa Eyin Ni Oluwa o, Jehovah Eyin Ni Oluwa O, Oba wa Eyin Ni Oluwa, Jehovah Eyin Ni Oluwa, oba wa