TANI

by Sola Allyson

Tani mo gbekele ti mo fi n s'ayo Tani mo gbekele ti mo fi n gbe'se mo ngbe Tani mo gbekele ti mo fi n yan Repeat Adlib: Tani tani gan Mo ń gbese mo ngbe Igba eru ba mi sibe mo n s'ayo (Mo ń s'ayo) Igba eru ba mi sibe mo n gbe'se mo ngbe (Mo n gbe'se mo ngbe) Igba eru ba mi sibe mo n yan Igbagbo ireti l'o mu mi n s'ayo (Ayo ninu Baba mi) Igbagbo ireti l'o mu mi n gbe'se mo ngbe (Mo n tesiwaju oo) Igbagbo ireti l'o mu mi n yan Tani mo gbekele ti mo fi n s'ayo Baba ni mo gbekele ti mo fi n gbe'se mo ngbe Oun mo gbekele ti mo fi n yan Igba eru ba mi sibe mo n s'ayo (Nitori mo j'omo Baba) Igba eru ba mi sibe mo n gbe'se mo ngbe (Mo n gbe'se mo n tesiwaju l'ona naa) Igba eru ba mi sibe mo n yan Igbagbo ireti l'o mu mi n s'ayo (Eni gbeke l'Oluwa kò ni j'ogun ofo) Igbagbo ireti l'o mu mi n gbe'se mo ngbe (B' ti le wu k'o ri mo n gbe'se mo ngbe) Igbagbo ireti l'o mu mi n yan Ninu igbekele aanu ti kii sa Iyen lo mu mi de'bi o wa titilai Aanu t'o bà t'o si wa ko le gbòn mi re, bi mi o ba ti jò re o wa titilai O wa titilai, o wa titilai Aanu t'o ba t'o si wa ko le yìn mí nù, bi mi o ba ti joo re o wa titilai Ore ofe ki n ma lo joo re ni mo nwa sii, ileri t'o se t'aa si maa se ko le ju mi le, aanu t'o mu mi de'bi si wa ko le tan lailai, bi mi o ba ti joo re o wa titilai O wa titilai o O wa titilai O wa kò le tan O wa titilai Aanu t'o ba t'o si wa ko le gbòn mí re lailailai, bi mi o ba ti joo re o wa titilai Ìtònà ni mo gba ki n le maa s'ayo Iranwo ni mo fe lati maa rin'na yi Imole k' maa tan bi mo ti nlo Ad lib: Ìtònà ni mo gba Ìtònà ni mo bèbè fun o Imole a maa tan Ìtònà lat'oke wa Ìtònà k'o wà fun mi l'ona mi Lati maa rinna yi o Ìtònà lat'oke wa Igbekele mi wa ninu Baba oju ò le ti mi lailai Mo n tesiwaju l'ona naa, mo ng'oke si l'ojojumo ni Imole k' maa tan bi mo ti nlo Iwaju iwaju l'òpa ebiti mi a maa re si o Imole k' maa tan Imole k' maa tan bi mo ti nlo. --- www.LRCgenerator.com ---