Sola Allyson's Classics (Live)

by Sola Allyson

Olohun kii mai se ibi Olohun kii mai se ibi Olohun kii mai se ibi Olohun kii mai se ibi Gbogbo ohun t'olohun da Dara Dara ni Botilewu ko joo ibi to Ire lo ma ja si A ni lati bebe fun oye orun o Ka le rin arin ye laye A ni lati bebe fun oye orun o Ka le rin arin ye laye Aseyi owu lolorun Sugbon sibe sibe ire ni All things are working together for your good Sibe sibe ire ni Bo ban gba ire lojojumo Ma yo layo ju Bo ban gba ibi akunwosile Ma fi were pe eleda lejo Eyi to wu koje tire All things are working together for good Olohun kii se ibi