Mo Juba

by Sola Allyson

Mo juba oba Mo juba oba Iba eledumare to ni gbogbo ogo Aterere kari aiye olorun awon omo ogun Mo juba oba Mo juba oba Iba eledumare to ni gbogbo ogo Aterere kari aiye olorun awon omo ogun Mo juba oba Iba eledumare oba to ni gbogbo aiye Eni nla to nbe lori ite titi lailailai Emi mi bola fun o Lati ogbun okan mi, mo yi ka otun Mo yi ka osi mo pa rubu rubu Fe ni na oba aponle julo eni aiyeraye Iwo lo tin be iwo yio si ma be Leyin re ko si mo oba titi lai Mo sin o mo sin o o sin o lati ogbun emi mi Eni na oba na oluwosan alanu Gbogbo eda ati emi ahun bu ola fun o Mo juba oba Mo juba oba Iba eledumare to ni gbogbo ogo Aterere kari aiye olorun awon omo ogun Mo juba oba Iwo ni oba ti o le papo da lailai Oba to ti wa ti yio si ma be titi Aiye mi yio ma fi ibukun fun oruko re Ileke ola ipinle oye opin gbogbo ola Gbogbo ise yio ma yin o aahn pe o loba Iwo ni alanu to fe bu se mi loso Otun fi ogo die kun fi gun mi lade Odo re na ni mo gbogo na pada si oluwa Eni na oba na oluwo san alanu Gbogbo ise da ati emi ahn bola fun o Gbogbo ise da ati emi ahn bola fun o Ohun ta ri ati eyi ta o ri won bola fun o Won bola fun o Loko orun lagbede meji ile tan te Ahun bola fun o Iwo lo ni ike to po alanu to po, olola to po Ahun bola fun o Ko sede na ni gbogbo aiye ti iro ogo re kin buyo Ahun bola fun o Iru okun bola fun o osa na bola fun o Ahun bola fun o Gbogbo ise gbogbo ede ijoba lon wa riri fun oruko re Ahun bola fun o Gbogbo ise ati emi Ahun bola fun o