Mímọ́ Ni Ọ́ (Live)

by Sola Allyson

mimo ni o mimo ni o, mimo ni o, mimo (x2 Oluwa Olorun Eledumare, topo nipa at'agbara Chris: mimo ni o.... Gbogbo iseda son be, emi naa so be Lati ogbun emi mi, mo juba Mo juba re, oba mimo Mo wole fun o, oba toto Leyin re e, kosi o Iwo nikan ni oba (x2 Mo wari fun o olola, imole Titan sinu okun mi, ogo foko re Leyin re e, kosi o, iwo nikan ni oba (x2 Mimo ni o, mimo ni o, mimo Aye ati orun nsoro ogo re, an fi ise owo re han Iwo mimo Mo da ohun mi pomo gbogbo ise re, emi, emi mi ati emi mi, ansi o nigbagbo Oba towa ni ipekun ola, ipekun ogo, ipekun agbara, ipekun ewa, iwo ni agbara Pipe loje naa Oluwa Pipe ni o, pipe ni o, pipe e (x2 Yiye ni o, yiye ni o, yiye Tito ni o, tito ni o, tito Gigun ni o, gigun ni o, gigun Mo juba re, Oba mimo Mo wole fun oba toto Leyin re kosi o, iwo nikan ni Oba Mo wari fun o, olala, imole to tan sinu okun mi, ogo foko re, leyin re e, kosi o Iwo nikan ni Oba