MIMO

by Sola Allyson

Mimo ni O mimo ni O o mimo Mimo ni O mimo ni O o mimo Ad lib: Oluwa Olorun Eledumare t'O po n'ipa ati agbara Gbogbo iseda nso bee emi naa mo so bee Lat'ogbun emi i mi Mo juba Re Oba mimo Mo wole fun Oba toto L'eyin Re, ko si o Iwo nikan ni Oba (Repeat) Ad lib: Awamaridi Oluwa Iwo t'O wa n'ipekun imole, Iwo ni ekun ola, ekun ogbon, ekun agabara Oba t'Ó joko s'ori Ite, Oba t'Ó wa l'ori obiri aye maa s'ola a Re lo Aye ati orun nbo O, kos'elomiin t'o ye ko gba ijuba wa bi o se'Wo Mo wari fun O o Olola Imole t'O ntan s'inu ookun mi ogo f'ooko Re L'eyin Re ko si o Iwo nikan ni Oba L'eyin Re ko si o Iwo nikan ni Oba Ad lib: Pelu iwariri lat'ogbun emi mi Kos'elomiin Iwo ni, l'eyin Re Iwo naa ni Olugbemiro, Olusaaanuumi, Olukemi, Olufunmilebun, Olugbemiro, Iwo nikan Olutimileyin Mimo ni O mimo ni O oo mimo Aye ati orun ns'oro ogo Re a n f'ise owo Re han, Iwo, mimo Mo da ohun mi po mo gbogbo ise Re, emi, emi i mi ati eemi i mi a nyin O nigbagbogbo, Oba t'Ó wa n'ipekun ola, ipekun ogo, ipekun agbara, ipekun ewa Iwo nikan ni Oluwa Pipe naa l'O je Oluwa Pipe ni O, pipe ni O o pipe (Ta l'o le yo kuro ninu Re nigbat'a o tie mo) Yiye ni O yiye ni O o yiye (Iwo naa l'O wa fun'ra Re Iwo ni Oluwa, Odo Aguntan t'O joko s'ori Ite o yiye) Tito ni O tito ni O o tito (Tito ni O Eleda gbogbo iseda, Olutoju gbogbo eniyan, Olorun gbogbo eran ara, Eniti ngbo adura odo Re l'a nwa Iwo ni) Gigun ni O gigun ni O o gigun (Oba t'O joko s'ori obiri aye, O fi aye so'le s'ori awon isan omi, aye ò le ri lailai ko le ri ise e Re ni, gigun, o gun lailai) Mo juba Re, Oba mimo, etc Ad lib : Emi mi n juba Re nigbagbogbo L'eyin Re kos'elomiin I confess kos'elomiin Olorun Eledumare t'O po n'ipa ati agbara Iwo ni o Olorun awon'mo ogun Iwo nikan Tani m ba juba bi o se'Wo Olori egbegberun ogun awon angeli Iwo ni Oluda aye kos'elomiin Aseda gbogbo eniyan, Olorun gbogbo ede, Olorun gbogbo eya Emi mi, eemi mi, ati emi naa Imole t'o ntan ti ò le ku lailai Olugbemiro, Olusaanuumi, Olugbamila, Oluyomi ninu okunkun L'eyin Re ooo Tani m ba sin bi o s'Enit'O gba mi la, Eniti mi ò ri sugbon ti mo r'ise Re ninu aye mi Iwo nikan ni Oba Ad lib: Olorun gbogbo araye Iwo nikan ni Olutoju gbogbo eniyan Iwo nikan ni Mo ki O ki O Iwo nikan ni Oba Maa s'ola Re lo, maa s'ola Re lo kos'elomiin You Are The only One, You Are The only One Iwo nikan, Holy, mimo mimo ni O Iwo ni Oba Iwo nikan ni Oba. --- www.LRCgenerator.com ---