IRI

by Sola Allyson

Gbe mi wo l'otun mo te'wo Ìri k' se le mi o Gbe mi wo l'otun mo te'wo Ìrì ko se le mi o Imole k' tan l'otun s'ona mi (Ko tan ko tan ko tan ko ni ku lailai, itura ko ba) Itura k' ba le mi lat'odo Re (Oluwa t'Ó ni emi mi) Gbe mi wo l'otun mo te'wo Ìrì k'o se le mi o Repeat Ad lib: Mo jowo emi mi fun O Enit'O ni emi mi Imole k' tan Imole lat'oke wa k' tan Enit'O fi ebun se mi l'oso Gbe mi wo, gbe mi wo l'otun To mi s'ona lati rin Olutona mi Okunkun k' ká kuro tan'mole otun, ki nrin l'ona naa t'oO fe oye k'o ye mi, maa ri maa mo oye á ye mi ninu ife Re Gbe mi wo, etc. Ad lib: Mo jowo emi mi fun o, Enit'O ni emi mi Gbe mi wo l'otun, mo jowo okan mi fun O Enit'O ni okan mi Mo te'wo mi o lat'oke wa iri ko se, ko se, ko se, ko se le mi Imole ko tan, ko tan ko tan ko ni ku lailai, imole ona mi o ni ku lailai, itura ko ba o, o ba, o ba, o ba le mi lat'odo Re. Irin aye o see da rin lai si emi Re, mo jowo okan mi fun O Enit'O ni okan mi Nigbati idanwo ba de - Oluwa so mi Ona maa nsu nigba mi, nigbati ona mi ba su Oluwa o - Adaba to mi Imole lat'orun k' tan s'ona mi, ko maa tan nigbagbogbo o - Ona yen k'o mase di Agbara l'aye at'orun owo Re lo wa kos'elomiin l'eyin are - Iwo nikan ni Iwo nikan naa n mo fe - Saa maa to mi lo Nigbati o re okan mi o - Ìrì se le mi o --- www.LRCgenerator.com ---