Imole

by Sola Allyson

Chorus Jesu Imole ati Egan ati afara, sibi imole Jesu eni towaa, ife baba, feni tofe domo. Jesu Imole ati Egan ati afara, sibi imole Jesu eni towaa, ife baba, feni tofe domo. J-e-s-u eni naa eni naa to waa, ife baba, feni tofe domo. Call: Jesu ooo Resp: Jesu, Imole ati Egan ati afara, sibi imole Cal: Alagbawi mi, Iwo ni Jesu Resp: Jesu, eni towaa, ife baba, feni tofe domo. Stanza 1 Imole, lati inu imole o wa lati dawa pada sodo imole okun to gbaye ko je ko' mo imole won dite mon-on ife baba O-lo-run didun eniyan, eniyan o didun die iwon aguntan, sinu ile aanu Ipase eniti mo gba igbala ati ilaja sodo baba, baye ti fifunni ko imole sookun aye mi ohun lo seto emi mi. Chrs. Jesu Imole ati Egan ati afara, sibi imole J-e-s-u (Okan mi n saferi re nigbagbogbo, alasepe igbala mi) Jesu, eni towaa, ife baba, feni tofe domo. Call: (Emi mi ke rara, mo pe J-e-su, alagbawi mi, Oku, Emi ye) Jesu, Imole ati Egan ati afara, sibi imole J-e-s-u, eni towaa, ife baba, feni tofe domo. Stanza 2 Eni wa imole won a ri imole bi won o mo imole, won a dite imole Irora yan po gan Eje ati Omi san gan-an sibe o sakawe funwa pe, baba darijiwon won o mo ohun tonse sa ti mohun a nse baba darijiwon oo, nitori Imole, ninu Irora, o tun fi iyonu wole itara O ni Iya wo omo re, omo wo iya ree O kigbe lohun rara, Olorun mi eese ti o komi sile, eese to jumi'le, eese to jumi'nu Ife po gan oti kikan laye fun awon ton wa imole won fiya je imole O ba pari, o pari (Imole femi e sodo baba O pari) Nitori imole, nitori imole aso ipele ya oo Nitori imole, a le pe baba ni baba Nitori imole isa oku dofo Eni bafe le waa domo. Jesu, oga-ogo Olori Ogun Orun Omo alade alaafia Alase orun Aye e baba, baba laye o, baba layee Aye mi tire nii tan imole nipase mi Ogo mi ko fogo fun o Ola mi ko bu ola fun o Chrs J-e-s-u Iwo ni imole Iwo ni afara sibi ategun I-mo-le J-e-s-u Iwo ni eni naa towa mo juba re eni to so mi domo mo juba re, eni to so mi domo, tire ni aye mi itansan imole latodore, mo juba re Olugbala mi Alasepe Igbala mi eni to so mi domo Mo juba re eni to so mi domoo