Igbagbo

by Sola Allyson

ba miran o ma se mi bi kin pada seyin Igba miran o ma se mi bi kin jowo re Igbati ji aiye ban ja bi pada seyin Igba tokan mi gboruru bi kin jowo re Sugbon mom o iwo ni eni ti kin koni sile Beni mom o iwo ni eni to solododo Sugbon mo gba iwo ni eni ti kin ko ni sile Beeni mo gba iwo ni eni to solo dodo Igbagbo mi duro lori ododo re Iwo lapata aiye raye ibi isa di mi Bo kan mi po ruru ko le pase re da lailai Iwo solododo mo si mo o ni alanu Igbagbo mi rom o iwo agabara mi Oke ni mo fo kan si ibi ti iranwo gbe wa Fun mi okun ati oke wa kin ma se pada seyin Kin ma sise ninu iriri kin ma se jowo re Tori mom o iwo ni eni ti kin koni sile Beeni mom o iwo ni eni to solododo Tori mo gba iwo ni eni to kin koni sile Beeni mo gba iwo ni eni to solododo Iriri aiye a ma fe sona eni ti o ni igbagbo Sibe mi o gbekele ohun ka leyin agbara re Ogbon ori eyan ole lo jaja eto to ni lailai Ko da bokan mi se ye meji Ileri to se o duro abrahamu sarah won rerin lowo Tori oda bi pe yeye ni Nibe won de ti to ppo si kun ibkun pipe Fun mi lokun atoke wa iwo ni alatileyin Kin ma subu kin lajo yi ja kin jowo re Tori mom o iwo ni eni ti kin koni sile Beeni mom o iwo ni eni to solododo Tori mo gba iwo ni eni ti kin koni sile Beeni mo gba eni ti kin solododo Mo mo daju eni ti kin koni sile beeni mo gba iwo ni Eni to solo dodo Tori mo gba iwo ni eni ti kin koni sile Beeni mo gba eni ti kin solodo