#CHILD

by Sola Allyson

ild Written and Composed by Sola Allyson Produced by Olaitan Dada I am a child of The Almighty Mo gbo o mo gbo (repeat 4x) Okan mi gbo ma gbagbe ileri naa Mo gbo o mo gbo A ti rà mi pada mo ti di omo Mo gbo o mo ti gbo (Repeat) Repeat Ad lib: Omo Baba l'emi se Omo Eledumare Olorun oga ogo l'emi Okan mi ma gbagbe ileri yen ko le ye lailai ko le ye beeni Forget no, forget not, forget not Okan mi gbo ma gbagbe lailailai! I am a child of The Almighty Mo gbo o mo gbo Om'Olorun oga ogo l'emi i se Mo gbo o mo ti gbo I am a child mo wa n'ipo omo Mo gbo o mo gbo I am a child of The Almighty Mo gbo o mo ti gbo Okan mi s'o gbo ma gbagbe ileri igba irapada re s'o gbo k'o yaa gbo A ti ra mi pada mo ti di omo Mo gbo o mo gbo Okan mi s'oo gbo ranti ileri naa nigbagbo mo gbo mo gbo Okan mi ji ma sun ma gbagbe ileri yen, mo gbo o mo ti gbo I am a child of The Almighty, etc Ad lib: Mo gbagbe osi mi bi omi t'o nsan lo, mo gbagbe iya mi bi omi t'o nsan lo, ojo aye mi tan'mole jade. Okunkun mi dabi osan gangan, imole de, imole wole omo Baba Imole l'emi i se My soul wake up within me forget not, forget not Omo Baba l'emi i se Eru le b'omo Baba sugbon ibi ò le sele d'omo Baba nitori Baba wa l'ehin omo Baba! Ji okan mi, ji okan mi, okan mi ji o ma gbagbe ileri naa, ji okan mi (Repeat) Mo ti di omo, yes, mo ti di omo The Spirit of adoption is upon my soul mo ti di omo Mo ti di omo, emi ti di omo Eru le b'omo Baba sugbon ibi ò le sele d'omo Baba nitori Baba wa l'ehin omo Baba mo ti di omo I am a child of The Almighty, etc Ad lib : Ajaga mi ti bo I am a child, a ti we mi mo I am a child Omo Baba l'emi i se Imole tan s'ona mi ko ni ku lailai Ma gbagbe ileri yen ileri igba irapada re I am a child of The Almighty Mo gbo o mo gbo o I am child of The Almighty Mo gbo o mo ti gbo Okan mi gbo ma gbagbe ileri yen, ileri t'aa se nigba irapada re, I am a child. I am a child. I am a child. I am a child. --- www.LRCgenerator.com ---