Alujanjankijan ft. Adekunle Gold

by Sola Allyson

Iya iya ta kun wa le (Alujanjankijan) Iya Iya ta kun wa le (Alujanjankijan) E ma fi omo si le fun iyaje (Alujanjankijan) E ni to bi omo lo ye ko wo omo (Alujanjankijan) Ba mi na omo mi o ye ko de nu olomo O ju merin lo bi omo sugbon lgba oju ni wo omo Omo ta ko agbe le ta ko ta Omo ta to ake esho ta ni ta Omo ni gbeyin omo lola Omo lola omo ni yin Omo lade omo lewa Omo lesho ooooooo Oda bi o da ole da Osan bi o san a de san Igboya ati adura ni ogba yi o daaaa Iya Iya ta kun wa le (Alujanjankijan) Iya Iya ta kun wa le (Alujanjanjkijan) E ma fi omo si le fun iyaje (Alujanjankijan) E ni to bi omo lo ye ko wo omo eto omo (Alujanjankijan) Ori fun wa lomo rere bi ti Samueli o Wan ko Samu ogbe ko o si seun re If you spare the rod you go spoil the child I hope you know Train dem with the love of God i beg o Tori alai gboran omo (Ashani) Agba oku won loju (Ashani) Agba o jo won lo ju (Ashani) Agbaya ni o da (Ashani) Alai gboran omo (Omo ni) Wan de ni yan lola (Omo ni) Ta ba to wan dada o (Omo ni) Won de ni yan lola Iya Iya ta kun wa le (Alujanjankijan) Iya Iya ta kun wa le (Alujanjankijan) E ni to bi omo lo ye ko wo omo (Alujanjankijan) E ma fi omo si le fun iyaje (Alujanjankijan) Iya Iya ta kun wa le (Alujanjankijan) E ma fi omo si le fun iyaje (Alujanjankijan) E ni to bi omo e lo ye ko wo omo e eto wan (Alujanjankijan) Iya mama ta kun wa le o (Alujanjankijan) Kekere lan tin peka iroko to ba dagba tan ebo ni o ma gba Owun taba fi sile lewure n gbe Ke wure aiye ma ma gbe wa lomo lo Omo ta ba to ekun aiye agbe lo Ke kun aiye ma ma gbe wa lomo lo Iya Iya ta kun wa le (Alujanjankijan) Iya Iya ta kun wa le (Alujanjankijan) Iya Iya ta aaaaaaaaaa (Alujanjankijan) Iya Iya ta kun wa le ooo (Alujanjankijan) Edumare ko ba wa to omo wa o (Alujanjankijan) Edumare ko ba wa to omo wa (Alujanjankijan) Children are the heritage of the Lord o (Alujanjankijan) Egbo omo lola Omo lade omo lewa omo lere Ka fa ye si le ka to omo wa o (Alujanjankijan) They are the future generation (Alujanjankijan) Iya Iya ta kun wa le (Alujanjankijan)