AJITANNAWO

by Sola Allyson

itannawo Written and Composed by Sola Allyson Produced by Latechs Eni à ba ta k'a fi r'atupa ni mi Ajitannnawo ti mo da ope l'o ye'Lu O to mi s'ona t'o ye n gba t'Oba l'ope Ade O de mi mo gbe kale niwaju Re Mo te'ri okan mi ba o s'Olorun mi Repeat Ajitananwo ti mo da - Ope mo mu wa Ajitannawo ti mo da - Ope mo mu wa Irugasoke ko rara - Mo s'ope f'Olu Anu mo ri gba - emi ko o ope Irugasoke ko rara mo s'ope f'Olu Aanu mo ri gba emi ko ope Iboju ya ewon bo eru mi fuye Ile oro ti mo wo ope Eni à bá tà ka fi r'àtùpà, etc. 2. Ago igbala ni mo gbe ope Maa polongo oro yi titi Kos'ohun to wa ti Baba ò le tan Eni wa l'eyin ogba yara wole Iboju á ya ewon á bo eru re a fuye o Ago igbala l'emi gba ope! Eni à bá tà k'a fi r'atupa, etc Ajitannawo ti mo da - Ope Ajitannawo ti mo da - Ope Aanu Oluwa lo gba mi o - Ope Ko jo pe bayi laa ri o - Ope Yiyo Eleda ni mo ri o - Ope Fun gbogbo anfani ati iranwo ti mo n ri lo - Ope Aanu po l'odo Baba wa - Wa Eni wa l'eyin ogba wole wa o - Wa Iwo naa wa o si wa - Wole Iwo naa wa yara maa bo - Wole Irira t'o bà sori ogo - A tan Idamu t'o wa lori ogo - A tan Iwenu a sele omo o - Waa bo Okun a ja, ewon a bo, iboju a ya Iri a se s'ori ogo - Itura a de Imuse a wa itura a wa - Itura a de Ajitannawo ti mo da - Ope Ago igbala ti mo gba - Ope --- www.LRCgenerator.com ---