Ancient Worship Medley ft. Dare Justified

by Paul Tomisin

I wo lo ni wa Baba mode o ( jesu) aiye mi dowo re bami tun se Sebi iwo lamokoko aiye mi ooo oluwa mo mi mo mi bo se fe To ba mo mi aiye mi a lojutuu To ba mo mi aiye mi a sun wo Sebi wo lamokoko baba mo mi bi o ti fe Oba ti n gbo Ekuñ aladura mo ti de(x2) Gbe ja mi ja gbo ro mi ro ma je n gba gba nu Adura I ro didun lorin seraph , oruko didun ni awon, Orin ti o dun julo ni jesu jesu jesu Oloruko Aperire jesu oo ,oloruko apegbore jesu Iwo ni olutunu orun fun ore ati agbara re a nko aa nko a nko Halleluyah Halleluyah lo mumi goke modupe Halleluyah lo mu mi goke ninu ewu Halleluyah lo mumi goke mo awon ota lowo Halleluyah lo mumi goke odo Cherunim e yoo Seraphim e yoo A fi ipinle le le lo ri o ti to A fi ipinle le le lo ri ododo Ipinle ti jesu fi Lele leyi ti baba aladura gbo mo duro le Christi apata Gbo oun awon angeli ti n korin Won korin ogo ogo Won korin eye eye Eri orun sokale ko wa gbe wa ro Adaba Orun sokale mowa gbe wa wo Ro ojo ibukun re le wa Lori Le yin ipade wa yii jeka ri o ka to lo Aa mo fe ri jesu ki n ma wo ju re kin na korin kin na wo ju re ninu ogo re kin gboun soke A di ileri re mu pe wo yi o wa larin awa..awa ti o pejo loruko re Emi mimo e se o emi awon wolii Eyin kuku lagbara wa emimimo ese Mo fara mo olorun babalola Mo faramo olorun apostelii ona eyi ye mi o mo faramo olorun babalola Ri n larin wa oluwa rin larin wa Alagbara ma ni o o rin larin wa Ija Dopin ogun ti tan olugbala jagun molu Orin ayo la wa o ma ko Halleluyah Halleluyah