Èyan JÉSÙ ft. Monique & A'dam & Bidemi Olaoba

by Mike Abdul

Intro Wos Eyan Jesu Jesu lo ni Central Bank (eh.. Central Bank) Sister ṣẹṣẹde (ah.. Sister ṣẹṣẹde) Ma people Ma people (People) Oluwa lọ ni people á¹¢e you want to bring the street to church No, we want to turn the street to church, Ok Ma people Ma people The people I get who will gather together forever For better labari la sweeter orisa zativa Tomero porero ororo Oya dance eyan Jesu (eyan Jesu) Oruko ẹ lọ kọ s'ori blessing (eyan Jesu) Anu lọ ri gba eyan Messi (eyan Jesu) World best ọmọ ologo champion (eyan Jesu) cceeyan lo se bintin (eyan Jesu) Oritsejafor o jẹ ki n l'ẹnu (eyan Jesu) Oya put your name eyan Jesu (eyan Jesu) Hashtag eyan Jesu Oya fun wọn Lamba (Lamba) Lamb of God (Lamba) Tọ ba ṣe DNA test Fun awọn eyan Jesu l'oṣuyi, ṣ'o ma wa (ṣ'o ma wa) Sa 'rẹ wa gba Number (Lamba) Special Number (Lamba) Anyway you must to know what made the word Oluwa si ni Ọrọ na Oya gbe gbe ti (gbe gbe ti) Padi ẹ f'ẹhin ti (gbe gbe ti) Follow the Ladder (gbe gbe ti) Wọn fẹ koronate ẹ (gbe gbe ti) (Ayiii..) á¹¢o ro (koro) koro (koro) No ro (koro) Koro, l'obanikoro (koro) wọn ma ji soro, Koro Oya dance eyan Jesu (eyan Jesu) Orukọ ẹ lọ kọ s'ori blessing (eyan Jesu) Anu lọ ri gba eyan Messi (eyan Jesu) World best ọmọ ologo champion (eyan Jesu) cceeyan lo ṣe bintin (eyan Jesu) Oritsejafor o jẹ ki n l'ẹnu (eyan Jesu) Oya put your name eyan Jesu (eyan Jesu) Hashtag eyan Jesu Eleyi tun wa contagious (suya contagious) Ota l'ẹnu tẹtẹtẹ T'ẹ ba ngbọ praise party (praise party) Ọlọrun Ọba l'O ma play (Ọlọrun Ọba l'O ma play) Kiri gbogbogbo (gbogbogbo) Kiri gbagbagba (gbagbagba) Do your hand like this (do your hand like this) Sebi you wan receive (do your hand like this) á¹¢'o d'owo mọ (ṣ'o d'owo mọ) á¹¢'o fẹ sọ pe o mọ Jesu (ṣ'o fẹ sọ pe o mọ Jesu) You want to know, You want to know, eh.. You gat to know, You gat to know eh.. You gat to know your God Jehovah eh.. go go go ti go ti go wos, go go go ti go ti go take it Oya dance eyan Jesu (eyan Jesu) Orukọ ẹ lọ kọ s'ori blessing (eyan Jesu) Anu lọ ri gba eyan Messi (eyan Jesu) World best ọmọ ologo champion (eyan Jesu) cceeyan lo ṣe bintin (eyan Jesu) Oritsejafor o jẹ ki n l'ẹnu (eyan Jesu) Oya put your name eyan Jesu (eyan Jesu) Hashtag eyan Jesu Two thousand years lati bẹẹ̀rẹ̀ (bẹ̀ẹrẹ̀) Unstoppable bí ti Pelé (Pelé) Enemies wọn sa wọn nmi ẹlẹ (ẹlẹ) Wọn get ẹ, ẹhn ki lo ń ṣẹlẹ̀ Call us the sauce, call us the fire Ore-ọ̀fẹ́ yẹn no dey tire We no Retreat, we no Surrender Na we dey sell, na who be buyer A n seek when ni Mount Zion á¹¢e communion pẹlu lion O dabi Film mount Zion Jesu mi re ati triumph Oya f'ede fọ (Robo seke) Lai wo we (Robo seke) Mo s'ede ti o yẹ mi si nkan ti o yẹ mi, s'oluwa t'O ni gbgbo oye Oya dance eyan Jesu (eyan Jesu) Orukọ ẹ lọ kọ s'ori blessing (eyan Jesu) Anu lọ ri gba eyan Messi (eyan Jesu) World best ọmọ ologo champion (eyan Jesu) cceeyan lo ṣe bintin (eyan Jesu) Oritsejafor o jẹ ki n l'ẹnu (eyan Jesu) Oya put your name eyan Jesu (eyan Jesu) Hashtag eyan Jesu End