Iro Ayo ft. Omotola Jayeola (Mr. Gbera)

by Mike Abdul

eh oh eh oh ah oh oh eh oh eh oh ah oh oh iro ayo la o ma gbo nile wa sekere ilole ekun igbagbo lo so wa da segun let them know pa'loluwa awa oni l'oju ekun [laye] awa oni lereke ose ore ofe oluwa towa let them know pa'loluwa see enu ope wa o'gbolude [o'gbolude] òrun si ayo de o [saye] ayo olorun sa l'agbara wa wan ti mo pa'loluwa iro ayo eh eh eh eh iro ayo eh iro ayo lawa nfe o iro ayo eh iro ayo ninu le wa iro ayo nirin ajo wa aro ayo lori ise wa iro ayo eh iro ayo ninu le mi iro ayo nirin ajo mi iro ayo lori ise mi iro ayo eh once has he spoken twice have I heard all power belongs to God sing his praise with a shout of joy mimo l'oluwa [mimo] gbogbo aye kun ogo re [mimo] awon orun wan wa riri [mimo] almighty l'olorun wa ayobami ayomide ayomipo ayomikun gbogbo ayo ni mo kojo sir igbala ayo ti wole de iro ayo eh eh eh eh iro ayo eh iro ayo lawa nfe o iro ayo eh iro ayo ninu le wa iro ayo nirin ajo wa iro ayo lori ise wa iro ayo eh iro ayo ninu le mi iro ayo nirin ajo mi iro ayo lori ise mi iro ayo eh ayo ayo ni mo gbede eni ba ri mi e gb'ayo eni ba gbo mi e gb'ayo oun mbase ayo ayo ni mo gbede gbogbo oun mo dawo mi le lo yori s're kiise mimose ore ofe s'a ore ofe s'a o eh eh eh eh ayo ayo ni'se ayo ni'se