Dide ft. Tee Worship

by JayMikee

Dide! Ẹmi Oluwa Jehova mbẹ lara mi (Dide) Nitoriti o fi àmi orro yàn mi (Dide) Lati wasu fun awọn òtosi (Dide) O ti rán mi wá lati ṣe awotan oo (Dide) Gbogbo awọn onirobinujẹ ọkàn (Dide) Ati gbogbo awon alainireti (Dide) Kede idasilẹ fun awọn igbekun (Dide) Ati isile tubu fun awon ounde (Dide) Dide eee eh dide ooo (Dide), dide o Kristiani Oloogun (Dide) Kristiani maa ti wa simi o Ni angeli re wi Ni aarin ota lo waa, maa sora Maa sora, maa sora (Dide) Ogun orun apaadi (Dide) Ti a ko ri sugbon won ko ara won jo (Dide) Won nso e,won nso e, won nso e (Dide) Dide o, Dide oo, Dide ooo (Dide) Maa sora Kristiani (Dide) Igbagbo yi, O gbodo di mu(Dide) Dide o, Dide o (Dide) Dide ooo (Dide) Dide eee eh dide ooo (Dide), dide o Kristiani Oloogun(Dide) Kristiani Oloogun (Dide) Dide, Dide, Dide, dide