Igba Sa Lonigba Nlo

by Evang. Ojo Ade

Igba sa l'onigba n lo, asiko si ni gbogbo nkan l'aye L'orukô Jesu ômô Ôlôrun, igba t'emi ko ni k'ôja mi Ma gbe'nu ôrô wa f'aini p'itan o, orin ôpê o a gb'ęnu mi kan Igba sa l'onigba n lo, asiko si ni gbogbo nkan l'aye L'orukô Jesu ômô Ôlôrun, igba t'emi ko ni k'ôja mi Ma gbe'nu ôrô wa f'aini p'itan, orin ôpê o a gb'ęnu mi kan Ôrê gbô ôrô Ôlôrun B'ękun pę d'alę kan Ayô nbô l'owurô Lai si ogun, ara mi, eniyan kan ko le d'asęgun Ninu adura igba gbogbo Lai ręwęsi Isęgun daju Ibanuję rę a d'ohun itan o, Halleluyah a gb'ęnu rę kan Igba sa l'onigba n lo, asiko si ni gbogbo nkan l'aye L'orukô Jesu ômô Ôlôrun, igba t'emi ko ni k'ôja mi Ma gbe'nu ôrô wa f'aini p'itan, orin ôpê o a gb'ęnu mi kan Iwô baba f'ôkan balę, Arabinrin o lô t'ujuka Awôn isoro ninu, l'ode eyi t'o n d'oju k'ôkan rę O ro titi aye su ô, dię lo ku, wa laaja Ibanuję rę a d'ohun igbagbe, orin iyin a gb'ęnu rę kan Igba sa l'onigba n lo, asiko si ni gbogbo nkan l'aye L'orukô Jesu ômô Ôlôrun, igba t'emi ko ni k'ôja mi Ma gbe'nu ôrô wa f'aini p'itan, orin ôpê o a gb'ęnu mi kan Awôn isoro aye rę, o le koko bi irin o Ati sanwo ile ogun, jiję, mimu inira l'oję Gbogbo aso pata lo ti śa, ati ramiran ko si r'ôrun Mo wi fun ô, o ni ra si Sa ma gb'adura, ogun rę a sę Osi at'are a d'ohun igbagbe, Halleluyah a gb'ęnu rę kan Igba sa l'onigba n lo, asiko si ni gbogbo nkan l'aye L'orukô Jesu ômô Ôlôrun, igba t'emi ko ni k'ôja mi Ma gbe'nu ôrô wa f'aini p'itan, orin ôpê o a gb'ęnu mi kan Ękun, ose mi a d'opin o (Halleluyah a gb'ęnu mi kan) Iwô agan wa yô l'ôdun yi o (Halleluyah a gb'ęnu rę kan) Alaisan yi, o ma ni ra si (Orin ôpê o a gb'ęnu rę) Alaini wa l'aluyo o (L'orukô Jesu, ninu ôdun yi) Iwô aboyun wa sô l'ayô (Halleluyah a gb'ęnu rę kan) Onisowo wa j'ere l'aye (Orin ôpê o a gb'ęnu rę kan) Onise ijoba wa gba 'gbega (Halleluyah a gb'ęnu rę) Ômô ile-iwe wa s'aseyôri o (Orin ôpê o a gb'ęnu rę) Gbogbo ęyin t'ę n gbô mi o (Halleluyah a d'orin awa) Gbogbo ęyin t'ę t'ęti si mi o (Halleluyah a d'orin awa) Igba sa l'onigba n lo, asiko si ni gbogbo nkan l'aye L'orukô Jesu ômô Ôlôrun, igba t'emi ko ni k'ôja mi Ma gbe'nu ôrô wa f'aini p'itan, orin ôpê o a gb'ęnu mi kan Igba sa l'onigba n lo, asiko si ni gbogbo nkan l'aye L'orukô Jesu ômô Ôlôrun, igba t'emi ko ni k'ôja mi Ma gbe'nu ôrô wa f'aini p'itan, orin ôpê o a gb'ęnu mi kan