Keresimesi Odun De

by Evang. (Dr). Bola Are

ti:Evang. Bola Are- Keresimesi Odun De] Keresimesi odun de odun ma de o Adupe lowo olorun to tun mu wa ri odun tuntun Aseyi ao tun se amo dun o baba Opolopo lajo beere odun yi Opin re jesu omo olorun Adupe lowo re kin se pe a fin yo won o A fin gboruko re ga ni o baba o Ope titi lowo olore nitori eni a se lore ti o dupe O da bi olosha koni leru lo Ope oloore ada yi da tan Ope oloore a da re lare Ope oloore adantan kari kanse Edupe lowo baba fun ore re lori wa Ore lori oko ore lori aya ore lori omo Ore gbogbo ise wa ore lori gbogbo awon ebi wa Bi ko basi jesu oba ogo Gbogbo elebo la ba ku si Gbogan oni wo san laba sun asi o Aso wa iba da so alaso Omo wa iba domo lomo Oko wa iba do'ko loko Ile wa iba di ile oni le Sugbon jesu lo gba wa lo woo ta ile at iota ode Gbogbo e wa ronu ki lo ye wa o oba ogo Oba wa alagbara jiga jiga Oba wa alagbala ade wure Araba nla se gbo kiji Oba wa lana oba wa loni Oba titi aye o oba wa adagba ma pa ro oye Aru gbo igba ani oba mi oba re oba gbogbo aye ooooooo INSTRUMENTAL A gbe o ga o baba a gbe ga o baba A gbe o ga o baba a gbe o ga o baba Kabiyesi alade wura a gbe o ga baba A gbe o ga o baba a gbe ga o baba A gbe o ga o baba a gbe o ga o baba Kabiyesi alade wura a gbe o ga baba A gbe o ga o baba a gbe ga o baba A gbe o ga o baba a gbe o ga o baba Kabiyesi alade wura a gbe o ga baba A gbe o ga o baba a gbe ga o baba A gbe o ga o baba a gbe o ga o baba A gbe o ga o baba a gbe ga o baba A gbe o ga o baba a gbe o ga o baba A gbe o ga o baba A gbe o ga o baba E ba wag be ga e ba ewa gbe ga o E ba wag be ga A gbe o ga o baba a gbe ga o baba A gbe o ga o baba a gbe o ga o baba A gbe o ga o baba a gbe ga o baba A gbe o ga o baba a gbe o ga o baba Kabiyesi alade wura a gbe o ga baba Ere ti a fin se ajodun keresimsi lododun Ohun ni a ri ninu iwe John ori keta ise kerin din logun to so wipe Nitori oloru fe araye be ge O fi omo re kansoso fun ni Ki eni keni ti o gba gbo ma bas se gbe Sugbon ki o le ni iye ani pe kun Ohun a tun ri ti oro iwe Isiah ko Ori kesan ese ike fa le so pe Nitori a bi omo kan fun wa A bi omo kruin ka fun wa Ijoba yio wa lejika re o A o si ma pe oruko re ni iyanu Olu da moran olorun alagbara o Baba ayeraye omo alade Alafia Olugbala na ni a bi fun wa la si ko keresimesi yi o Ohun ni afi se iranti re lodo dun olorun ma fe araye to be ge Eni to le yan da omo re kansoso fun araye Ogo ni fun baba ati fun omo ati fun emi mimo Ati meta lokan so so soso Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia Pe a bi olugbala fun wa Omo alade wura Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia Pe a bi olugbala fun wa Omo alade wura Ogo fun olorun loke orun ati fun re Alafia Pe a bi olugbala fun wa Omo alade wura Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia Pe a bi olugbala fun wa Omo alade wura Ise bi jesu olorun ran angeli gebraili lati lo bam aria wunda O pa de re ni galiie ti a pe ni nasaretti o Inje bi angeli ti de odo maria O ni Alafia iwo eni ti o ko ju si se lore Oluwa pelu re alabukun fun ni iwo Ninu awon obirin o Sugbon ni gba ti maria gbo Eru ba sugbon angeli na kiyesi O wipe ma baru maria ooo Nitori iwo ti ri oju rere ni odo olorun Sa ti kiye si iwo yio loyun ninu re Iwo yio si bi omo kun rink a n Iwo yio si ma pe oruko re ni jesu o Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia Pe a bi olugbala fun wa Omo alade wura Oro yi yam aria leun oni eyi yio ma fi se lese Nigba tie mi ko ti mo orunrin ri Ko sese ki oborin ko loyun layi mo okunri Otun so pe angeli ko so fun maria wipe Emi mimo yio to wa Agbara oga ogo ni yio sigi bo o o Nitori ohun mimo ta o tori e bi Omo olorun ni a o ma pe Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia Pe a bi olugbala fun wa Omo alade wura A gbo pe leyin iloyun maria Bi o ti je pe josfu penapena la bi fun Ohun a si ma se idile dafidi Leyin na ni ase jade lati odo ksari ogo to Pe ki a lo pa gbogbo eniyan Ni idile si idile Jsoefu ati maria Won joke lati naserti losi bethlemu o Nigbati won lo loju ona Osu measan maria oe ti o bi mo Ko si se yi pada mo dandan ni ko bi tori ase orun ni Won de bethlem aye ko si ni ile ero ,mo Sugbon ojo kuku ti pe o ti pen a Won ab ya si ibuje eran tara Ni be ni maria bi olugbala wa jesu krsiti si Omo alade wura mi o Ohun ni a bi si inuje eran Aye a olugbala mi ko ri ile wa si ooo Sugbon a dupe pe am ti olugbala o Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia Pe a bi olugbala fun wa Omo alade wura Leyin ti a bi jesu olugbala tan Angeli gabrile ti lo si odo awon oluso aguntan ni bethlemu o O yo si won ogo olorun si dapo Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia Pe a bi olugbala fun wa Omo alade wura