Hymns Medley

by Evang. (Dr). Bola Are

Intro nWonyi ni díè ninu Orin Inu iwe iyin rere ti CAC ti baba feran lati Ma ko ninu awon isojí gbogbo ibikibi ti won ba lo lati je iyin rere kristi ati lati wa elese ri, Baba wa apostle doctor timoteu Oluwole Obadare the WOSEM executive director. E ma ba wa kalo. Eniti o ba wa Jesu Bo ti gba ise lori agbelebu. Yoo ri gbala kikun gbalofe tori kristi lagbara Lati gbala. Chorus Eyin ayanfe olugbala npe yin Oreofe ati Orin eje yanu O ta eje re sile fun rapada Osi ni agbara lati gbanila.