Gba Aye Mi Oluwa

by Evang. (Dr). Bola Are

Gba aye mi, Oluwa, Mo ya si mimo fun O, Gba gbogbo akoko mi, Ki won kun fun iyin Re. Oluwa O Gba aye mi, Oluwa, Mo ya si mimo fun O, Gba gbogbo akoko mi, Ki won kun fun iyin Re. Oluwa O Gba aye mi, Oluwa, Mo ya si mimo fun O, Gba gbogbo akoko mi, Ki won kun fun iyin Re. Gba owo mi, Oluwa Ki nma lo fun ife Re, Gba ese mi fi se tire Ki ibukun je temi, lailai Oluwa O Gba aye mi, Oluwa, Mo ya si mimo fun O, Gba gbogbo akoko mi, Ki won kun fun iyin Re. Gba ohun adan mi, je ki nma Korin iyin fun o Gbe ete mi, olohun iyin re Je kin yin o titi aye Oluwa O Gba aye mi, Oluwa, Mo ya si mimo fun O, Gba gbogbo akoko mi, Ki won kun fun iyin Re. Gba okan mi, Oluwa K'ero mi je ti ihin rere Gba ogbon wa ninu okan mi F'okan mi se ibugbe tire, titi aye Gba aye mi, Oluwa, Mo ya si mimo fun O, Gba gbogbo akoko mi, Ki won kun fun iyin Re. Gba emi Jesu Oluwa Je kin fe o ju aye lo K'ife orun kun okan mi Tire lemi o se titi Gba owuro aye mi K'osan aye mi je tire Asale mi tire n'inshe Mo fi sile fun o Baba Oluwa O Gba aye mi, Oluwa, Mo ya si mimo fun O, Gba gbogbo akoko mi, Ki won kun fun iyin Re. Iwo Olugbo mi, boya o njo ni, abi o nba mi korin na lo Adun re ko ni mo munwa biko se oro iye ti nbe ninu re Ara kunrin, ati ara birin omode ati agbalagba Jesu npe o loni o nro o ki o fi aye re fun ohun Ki o ba le dara fun o Iwe romu, ori kejila, ese ikinni, wipe nitorina, mo fi iyonu Olorun be yin, ara ki eyin ki o fi ara yin fun Olorun ni ebo aye mimo itewogba, eyi ni ishe isin yin to tona Jesu fi emi re lele fun o ki o ba le ye Jesu wa saye lati wa gbeja larin eniyan ati Olorun wo mun bi arufin, a gun logo, a sha logbe a Da loro nitori re Ore kini iwo fifun Jesu loni O ki o a jowo aye re fun igba die, ti o ni lo ni aye Fi igbadun aye sile nitori fun igba die ni Fi agbere to ndun mo o sile nitori olojo lede lojiji Iwo jorun jorun ,bora bora aje ati gbogbo awon emi okunkun gbogbo fi eyi sile nitori Jesu dun ju be lo iwe mattew ori ogun Odin kan Ese ogbon odin meta wipe nigbana ni peteru dahun, o si wifun pe wo o, aawa ti fi gbogbo re sile, awa si tin to o lehin nje kini awa o ha ni Jesu si wi fun pe looto looto, ni mo wi fun yin pe eyin tin to mi lehin mini aye titun, ni igba ti omo eniyan yio joko lori ite Ogo re eyin yio si joko pelu lori ite mejila eyin yio ma se idajo awon eya Israeli mejila ati gbogbo eni tio file re sile tabi ara kunrin, tabi ara birin tabi baba tabi iya tabi aya tabi omo, tabi ile ni oruko mi won o ri oro ohun gba won o si jogun iye ainipekun iwe Timothy keji, ori kinni, ese kejila wipe nitori emi mo eniti emi gbagbo osi damiloju wipe, ohun le pa ohun ti mo fi lelowo mo titi di ojo na, ara ore, eema se atunwi asan mo fi aye re to Jesu wa loni, nitori Paul so fun wa mini iwe filipi pe ori keta, ese keje, sugbon ohun kohun to je si ere fun mi, a ohun mo ti ka si ofo nitori Kristi iwo Oni fayawo, ohun ki o wa fi ere sile ki ogba Jesu loni Tori igbaye yio kunna fun o layi gba Jesu, aro, osan, ale re ti Oluwa ni Nitorina so fun Jesu loni pe tinu tinu ni mo fi aye mi fun oo loni ni Jesu pe o, ma je o dola o Oluwa O Gba aye mi, Oluwa, Mo ya si mimo fun O, Gba gbogbo akoko mi, Ki won kun fun iyin Re. Oluwa O Gba aye mi, Oluwa, Mo ya si mimo fun O, Gba gbogbo akoko mi, Ki won kun fun iyin Re.