Eyin Oba Ogo/Okan Mi Yin Oba Orun

by Evang. (Dr). Bola Are

Ęyin Ôba ogo o, Oun ni Ôlôrun Ęyin Ôba ogo o, Oun ni Ôlôrun Yin fun isę iyanu rę ti o ti fi han O wa pęlu awôn ero mimô l'Ôrun O si ję imôlę wôn l'ôsan, l'oru Ęyin angęli didan lu duru wura Ki gbogbo yin juba t'ę n wo oju rę Ki gbogbo ijôba rę b'aye ti n yi lô Isę rę yio ma yin... isę rę yio ma yin Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi Ęyin fun irapada, ki gbogbo ôkan Ęyin fun irapada, ki gbogbo ôkan Ęyin fun orisun imularada Fun inu rere ati itoju rę Odamiloju pe O n gbô adura Ęyin angęli didan lu duru wura Ki gbogbo yin juba t'ę n wo oju rę Ki gbogbo ijôba rę b'aye ti n yi lô Isę rę yio ma yin... isę rę yio ma yin Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi Ęyin fun idanwo o, bi okun ifę Ęyin fun idanwo o, bi okun ifę To so wa pô mô awôn oun ôrun Fun igbagbô ti n sęgun, ireti ti ki n sha Fun ile-ogo t'o ti pese fun wa Ęyin angęli didan lu duru wura Ki gbogbo yin juba t'ę n wo oju rę Ki gbogbo ijôba rę b'aye ti n yi lô Isę rę yio ma yin... isę rę yio ma yin Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi Iwô ôkan mi (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi) Ôba ayeraye (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi) F'ibukun fun Oluwa ôkan mi (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi) Ôkan mi yin Oluwa Ôba awôn ôba (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi) Ęni t'o ra ô pada (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi) Ôba iyanu (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi) Atayerô t'o t'aye rę rô (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi) Alagbara giga (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi) Iwô ôkan mi yin Oluwa (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi) Yin Baba (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi) Yin Oluwa (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi) Yin Ômô Mary o (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi) Ôkan mi yin Ôba ôrun Mu ôrę wa si ôdô rę Wô t'a wosan, t'a dariji Ta la ba'a yin bi rę! Ôkan mi yin Ôba ôrun Mu ôrę wa si ôdô rę Wô t'a wosan, t'a dariji Ta la ba'a yin bi rę! (Yin Oluwa) Ôkan mi yin Ôba ôrun Mu ôrę wa si ôdô rę Wô t'a wosan, t'a dariji Ta la ba'a yin bi rę! Ôkan mi yin Ôba ôrun Oluwa awôn oluwa Atęręrę kari aye Emi iba l'ęgbęrun ahôn Ko ma to funyin rę o, Baba Ore t'o se fun mi l'ôdun yi Ôba nla t'o ra ęmi mi pada l'ôwô iku Ayeraye Atayerô bi agogo Iyin yę Ô o, ômô Mary o Ogo yę Ô o, Alagbara giga... o se Apata ijinlę me... ah Kabiesi t'o gba mi l'ôwô aye... O gba mi l'ôwô amôniseni Jesu t'o gba mi l'ôwô ôta ihinrere Oluwa awôn oluwa Ibi o ran mi ni mo lô Isę o ran mi ni mo ma ję o Alagbara ninu awôn ôrun Ah, igba t'aye gb'ogun de.... ase otitô ni Bibeli wipe Orukô Oluwa... Ile isô agbara ni Olododo wô nu rę o si ye O wipe Ologun ni Oluwa... Oluwa ni orukô rę Atayerô bi agogo... o gba mi l'ôwô iku O gba mi l'ôwô ôta Iyin yę Ô o... gbogbo aye mi n o fi yin Ô pata... pata Iyin yę Ô o... Ôba ôrun Igba t'aye gb'ogun de, Jesu wô inu ile wa Ęrujęję, Ękun ôkô Farao O bami lę m'agbara okunkun, gbogbo wôn fo jade pata Oluwa awôn oluwa... iyin yę Ô o... ogo yę Ô o Gbogbo aye mi t'o ku ma fi gbe Ô ga Ile mi a gbe Ô ga Ębi mi a gbe Ô ga Iyin yę Ô o Jesu mi, Oluwa iyanu Gbogbo ęni t'o ba m'ore Jesu k'o ba mi dupę Ôba t'o ra mi pada l'ôwô iku Ôba ti o ję ki awôn ôta ihinrere k'o r'ôrô sô Iyin yę Ô Baba mi... ogo yę Ô Baba mi Alapa jabijabi... Ara woo t'o wo iku t'ipinlę t'ipinlę Ôrô ati iye mi... Ôba ti mo gb'oju le Iyin yę Ô o Ôkan mi gbe Ô ga... aye mi gbe Ô ga Iyin yę Ô Jesu mi... ogo yę o Baba mi Mo dupę o... f'ore t'o se fun mi Ôkan mi yin Ôba ôrun Mu ôrę wa si ôdô rę Wô t'a wosan, t'a dariji Ta la ba'a yin bi rę! (Yin Oluwa) Ôkan mi yin Ôba ôrun Mu ôrę wa si ôdô rę Wô t'a wosan, t'a dariji Ta la ba'a yin bi rę! Oluwa o (Ta la ba'a yin bi rę!) Ôba awôn ôba (Ta la ba'a yin bi rę!) Jesu Kristi t'o gba mi l'ôwô aye (Ta la ba'a yin bi rę!)