To Ba Je Tere

by Chief Commander Ebenezer Obey

ba je tere Ati wa latise To ba je tijo Ke mu ra lati jo Keyin onilu mi filu si Kefeyi toku sile lodo mi To ba je tere Ati wa latise To ba je tijo Ke mu ra lati jo Keyin onilu mi filu si Kefeyi toku sile lodo mi To ba je tere Ati wa latise To ba je tijo Ke mu ra lati jo Keyin onilu mi filu si Kefeyi toku sile lodo mi To ba je tere Ati wa latise To ba je tijo Ke mu ra lati jo Keyin onilu mi filu si Kefeyi toku sile lodo mi Instrumentals Oro mi dori o dori O dori omo binrin Pelu omo kunrin kan Tiwon jo gbara won Oro mi dori o dori O dori omo binrin Pelu omo kunrin kan Tiwon jo gbara won Won mura tan lati se iyawo Baby ba ni a lo Won mura tan lati se iyawo Baby ba ni a lo T'ojo lowo T'ojo lola To ni moto repete Sisi olorun sogo Elele Lai fara gun Boro ba doju ru Sisi ba ni lo ni a lo Ara ile be baby ti ti Sisi Odale O ba ni lo ni a lo Ara adugbo be baby ti ti Sisi Odale O ba ni lo ni a lo Ebi oko be baby ti ti Sisi Odale O ba ni lo ni a lo Mase gbara lobirin o Mase gbara dobirin odale Mase gbara lobirin o Mase gbara dobirin odale Nigba ikanju won da e si le Won wa sofun e pe Iru e simi Iru mi si e Ta bo roye Asa kin fe e Maya folowo lo o e Instrumentals Odo omo binrin yi o more Odo omo binrin yi o more Odo omo kunrin o tenu morin Oni odo omo binrin yi o more Odo omo binrin yi o more Owo ko ni gbogbo nko Odo omo binrin yi o more Owo ko ni gbogbo nko Odo omo binrin yi o more Oro yi ka omo kunrin lara Owo ke titi O fese jo le Oro yi ka omo kunrin lara Owo ke titi Ofese jo le Oun ni ore nla Ni kalaya sile Ta ba laya sile To ba bimo fun ni Bi o ba si tomo Bobirin ba ko ni Wahala lo ko ni Iya mi ko, iwo ke Mase gbara lobirin o Mase gbara dobirin odale Mase gbara lobirin o Mase gbara dobirin odale Nigba ikanju won da e si le Won wa sofun e pe Iru e simi Iru mi si e Ta bo roye Asa kin fe e Maya folowo lo o e Emi si e Iwo sopo wire Omo kunrin be sisi titi Sisi Odale O ba ni lo ni a lo Ore oko be baby titi Sisi Odale O ba ni lo ni a lo Ebi oko kowe si sisi Sisi Odale O ba ni lo ni a lo Aseyinwa aseyin bo Bi oniya Won jade bi si e Otun belomiran lo Kiran kita to nbe Alaseju gbomilo Kiran kita to nbe Alaseju gbomilo Kiran kita to nbe Alaseju gbomilo Kiran kita to nbe Alaseju gbomilo Biwon ba so falaseju Ko ni gbo Kiran kita to nbe Alaseju gbomilo Ti won ba so falaseju A ta ku Kiran kita to nbe Alaseju gbomilo Ti won ba so falaseju A ta ku Kiran kita to nbe Alaseju gbomilo Instrumentals Kayode omo faloye 2x Kayode o oko iyabo o Kayode o oko iyabode Kayode 3x Kayode omo faloye 2x Kayode o oko iyabo o Kayode o oko iyabode Kayode 3x Akure nile Hmm oloye mekun Ile kayode o O oloye mekun Akure nile Hmm oloye mekun Ile kayode o O oloye mekun Ben carson o ose Chief kayode mi omo faloye Oko iyabode dele Baba ademola Baba ronke ronke Baba jemi ekijimi Baba segun aja segun Baba kunle o kunle * omo faloye Ema ale mo kayode mi Kin lenikan se tenikan ose ri Kin lenikan se tenikan ose ri Ema ale mo kayode mi Oko iyabode oko dele Ema ale mo kayode mi Ema ale mo kayode mi Ben caf Ema ale mo kayode mi ah Kin lenikan se tenikan ose ri Kin lenikan se tenikan ose ri Ema ale mo kayode mi Kayode faloye mi akure Ko seni to le yara si e Ko ma jiya Ko seni to le yara si e Ko ma jiya Ko seni to le yara si e Ko ma jiya Ko seni to le yara si e Ko ma jiya Ko seni to le yara si e Ko ma jiya Ko seni to le yara si e Ko ma jiya Ko seni to le yara si e Ko ma jiya Ko seni to le yara si e Ko ma jiya Kayode kayode Omo faloye Kayode kayode Omo faloye Kayode l'akure o Omo faloye Kayode kayode Omo faloye Oko iyabode Oko dele mi o Kayode kayode Omo faloye *