Suru La Fi Nsoko Obinrin

by Chief Commander Ebenezer Obey

suru lafin soko obinrin suru lafin soko obinrin agba to ni suru ohun gbogbo Loni agba Toni suru ohun gbogbo Loni Suru lafin soko obinrin okinrin kan wa baba toyin lounje oni mama kan mama toyin ni Ife won po pupo Ko se ko rara Won kin n ba ra won ja Aye ori arin won Ife baba toyin Opo si mama toyin oo Okunrin kan nbe Ma daru loruko re O nwa na lati tu won ka o