Sanu Olu
by Chief Commander Ebenezer Obey
Sanúolú omo oloye mase gbàrá le eniyan, nitorí aye ma soro. Sanuolu omo oloye mase gbàrá le eniyan, nitori aye má soro. Aiye Aiye gboká. Aiye Aiye soro o. Sanúolú omo oloye mase gbàrá leniyan, nitorí aiye má soro. Soyyo. Igbekele eniyan Àsan ni o, Asan. Igbekele eniyan asan ni o. Sanúolú boro kan ba yo, toba jòr àrá re. Iwo kanu so maba eniyan s rárá. Nitori onibaje làyé won feni fr o. Nigbati omin jegùn, ení kan ori e. Owa di igba ilabe, inu wa nbi won o. Pakúte mose nise on mekú o. Sanúolú o mo ise nise, orowolo o . Pakúte mose nise on mekú o, sanúolú o mo nise orowòl Sanúolú baba ewe o Sanúolú baba ewe o