Olowo L'aiye Mo
by Chief Commander Ebenezer Obey
Olowolayemo, Oluwa temi dowo re
gbogbo la la eda, nitori Owo ni
Jekaye mi dun, S'emi kin le jeniyan
Tete f'ona han mi, Maje kin lọ lofo
Oluwa Ko'sore to dabi re
Tete f'ona han mi, Maje kin lọ lofo
Jekaye mi dun, S'emi kin le jeniyan
Tete f'ona han mi, Maje kin lọ lofo
(Instrumentals)
Aiye kinse ile mi, Atigbo ni moje
awon angel pe mi, lati enu ona
(instrumentals)
Oluwa Ko'sore to dabi re
Tete f'ona han mi, Maje kin lọ lofo
Jekaye mi dun, S'emi kin le jeniyan
Tete f'ona han mi, Maje kin lọ lofo oooo