Odun Keresimesi

by Chief Commander Ebenezer Obey

nu odun ti mbe laiye Ti keresi loyato To t'odun ola rinri (Instrumentals ) Ninu odun ti mbe laiye Ti keresi loyato To t'odun ola rinri Keresimesi Odun de Keresimesi Odun de Odun olowo Odun olomo Edumare jeka sope oh Instrumentals Keresimesi Odun de Keresimesi Odun de Odun olowo Odun olomo Edumare jeka sope oh Instrumentals Odun titun to'n bo lona Baba je oseju emi wa Odun titun to'n bo lona Baba je oseju emi wa Aboyun ile obi tibi tire Aboyun ile obi tibi tire Eni to sowo Oma rere oja Eni ba gbomo dani Kaisan ma pa won Baba je osoju emi wa Instrumentals Wa eyin olooto Layo at'isegun Wa kalo wa kalo si Bethlehem Wa kalo wo o Oba awon angeli Kowa kalo juba re 2x Ewa kalo juba Si oluwa instrumentals Odun titun to'n bo lona Baba je oseju emi wa Odun titun to'n bo lona Baba je oseju emi wa Aboyun ile obi tibi tire Eni to sowo Oma rere oja Eni ba gbomo dani Kaisan ma pa won Baba je osoju emi wa Odun odun yi a yabo Odun yi a miri gidi Feregede la o ye o Odun odun yi a yabo Odun yi a miri gidi Feregede la o ye December ton bo lona Koni diwa meru lo Odun odun yi a yabo Odun yi a miri gidi Feregede la o ye o December ton bo lona Koni diwa meru lo Odun odun yi a yabo Odun yi a miri gidi Feregede la o ye o Instrumentals Irinse lo jona Obey o jona Ebami sope foluwa ogo Irinse lo jona Obey o jona Ebawa sope foluwa ogo Arinrin ajo alo si London Alo dawon laraya Arinrin ajo alo si London Alo dawon laraya London lagba de torinu Ni ilu Italy Kalo dawon laraya Lati ilu Italy Apada si London Atun dawon laraya Lati ilu Italy Apada si London Atun dawon laraya Okujo meta ka pada wale Okujo meta ka pada wale Ni isele yi sele Ina jo wa ni irin se Owe awon agbalagba Nipe oun tama seniyan Ti o ba se ko nigbo Amo adupe foluwa Bawo ni mba tise To ba se omolomo to lo jona mole Eka halleluyah feledumare Mo da mu su foba mimo Opelope oyinbo nile keji Opelope oyinbo nile keji To kingbe fa fa fire fire Ki pana pana to de Muti kekere oku ewu 2x Ewu ina ki pawodi Muti kekere oku ewu Muti kekere gbiyanju Osebi okunrin Sugbon e pa ogoro mo Lati omo ogunlade Osebi okunrin Sugbon e pa ogoro mo Alagba pass koragama Osebi okunrin Sugbon e pa ogoro mo Michele adio Osebi okunrin Sugbon e pa ogoro mo Ilori Lawrence ayodele Osebi okunrin Sugbon e pa ogoro mo Gabriel Adedeji Osebi okunrin Sugbon e pa ogoro mo Olohun iyo ke a minu Osebi okunrin Sugbon e pa ogoro mo * Osebi okunrin Sugbon e pa ogoro mo Mathew baba legba Osebi okunrin Sugbon e pa ogoro mo Opelope oyinbo nile keji To kingbe fa fa fire fire Ki pana pana to de A dupe lowo gbogbo eyin eniyan Eni to soju to seyin Peleni to ko leta ranse Ati gbogbo ero ni ilu oba Orioke ile la wa Irinse wa ni sale A o tete mo pe ile jo Opelope oyinbo nile keji To kingbe fa fa fire fire Ki pana pana to de Asese bere ere sise ni Ile oba to jo Ewa lo bu si Asese bere ere sise ni Ile oba to jo Ewa lo bu si Asese bere ere sise 2x Ile oba to jo Ewa lo bu si Asese bere ere sise 2x (outro)