Ko Sogbon To Le Da

by Chief Commander Ebenezer Obey

strumentals Ko sogbon to le da Ko si wa to le wu Ko sona to le mo To le fi daiye lorun o Ko sogbon to le da Ko si wa to le wu Ko sona to le mo To le fi daiye lorun o Instrumentals L'ojo ta ma bimo titun sile aiye Tonile t'alejo Lo ma ki ni kuewu L'ojo ta ma bimo titun sile aiye Tonile t'alejo Lo ma ki ni kuewu Ota omode Bere lati ibi iragoro Ka dani lounje nu Oti bere ota nini Ka dani lominu Oti bere ota nini Oti bo sowo aiye Instrumentals T'omo na ba ti Bere sin rin T'oba legbe Ti won jo se ere L'arin adugbo Ti obi e ba le Ra keke fun Oti bo sowo aiye T'oba ni ko gbe wa Kan jo fi s'ere Toba ni rara Oti dota won Oti bo sowo aiye Won ni Ma gbe keke e lo A o ba e sere mo T'ojo ba gori ojo T'omo na ba dagba To bere si ni Re ile iwe To foju si eko re Ton se dede Ti won ba se idanwo Toba se ipo kini O ti dota onipo kefa Won fu loruko Won l'omo teacher ni Instrumentals Aseyin wa aseyin bo Omo ojo si bere ise Oga ile ise Ni ko ma de bise L'agogo mejo On se dede On de bise lakoko Kin ba ibise je Awon ole afajo Wa fun loruko Won l'omo manager ni Oti bo sowo aiye Omo ton sise dede Oye ko lasiko igbadun Igba ti ofi jaiye T'oba lo si party Nibi ti won je igbadun Toba ni kilon mu Toba ni cocacola Wa ni ko maiye je Jedi jedi lo ma pa T'oba lo si party Nibi ti won je igbadun Toba ni kilon mu Toba ni cocacola Wa ni ko maiye je Jedi jedi lo ma pa Toba tu je Oga oni faaji Ton jaiye dede Champagne pelu schnapp To fin yanu Hienekens beer Stalagards top beer Vexbeer pelu guiness Gbogbo e loba lara mu Awon eda adamo Won fun loruko Otin l'alakorin Fowo e mu Instrumentals Toba tun wa l'oje Agba man To loso asiko Toju lobirin Won fun loruko Igberaga ti poju Ko mo jobinrin lo Sina l'alakorin fowo e se Toba tun je onisuru To kawe to gboye repete To dogbon jaiye Ti ki sapo Ti ko feran obinrin Awon eda adamo Won fun loruko Alakorin akada se lo woju koin koin Instrumentals O mu mi ranti Itan baba kan Pelu omo re Ti won si ketekete O mu mi ranti Itan baba kan Pelu omo re Ti won si ketekete Eshin pelu ketekete O dabi moto Ti won gun lo sode Eshin pelu ketekete Laiye ojo yen O dabi moto Ti won gun lo sode Ketekete ti dagba Baba pe l'omo e Won ba mura ode Won fe rin irin ajo kan Gege bi agbalagba Baba gun ketekete Omo re tele lo Bi won se rin siwaju die Won pade adamo Eda omo araye Omo araye ni awu Baba agbalagba Omo re rin nile Iwo gun ketekete Baba ba bosile lori ketekete Oba gbomo re sori ketekete Won ba mu irin ajo won po Won lo won lo won lo Bi won se rin siwaju die Won tu pade adamo Eda omo araye Omo araye tun ni awu Baba omugo orin nile Omo gun ketekete Baba ba tun stray Ogbomo sile Osare gun ketekete Otun gbomo sori ketekete Eni mejimeji lori ketekete Won mu rin ajo won po Won lo won lo Botun se rin siwaju die Won pade adamo Eda omo araye Omo araye tun ni awu Omo ti baba Alailanu ni yin Eyin mejeji lori ketekete E fe pa ketekete ni Baba ba woke titi Oni ma teyin lorun Eyin eda omo araye Baba ba gbomo sile lori ketekete Oun na bosile lori ketekete Ketekete lo lofo Baba pe lomo e Won fese rin tele Bi won tun se rin si waju die Won pade adamo Eda omo araye Omo araye tun ni awu Eyin mejeji eru aye niyin Erin nile ketekete lolofo Baba pe lomo re Gege bi mo ti wi Won bosile Ketekete lo ni waju Won fese rin tele Won ri si waju die Won pade adamo Eda omo araye Omo araye tun ni awu Eyin mejeji eru aye niyin Erin nile ketekete lolofo Baba bo boju oke Ofe ranti orin chief commander Oni edakun efeyi kogbon Kosogbon tele da Kosiwa tele wu Kosona tele mo tele fi daiye lorun o Kosogbon tele da Kosiwa tele wu Kosona tele mo Tele fi daiye lorun o Kosogbon tele da Kosiwa tele wu Kosona tele mo Tele fi daiye lorun o Kosogbon tele da Kosiwa tele wu Kosona tele mo Tele fi daiye lorun o Ile aiye Fun gbadi eni o Omo araye esere o Ile aiye Fun gbadi eni o Omo araye esere o Africa wuwa rere Rere lo pe Omo araye esere o Ile aiye Fun gbadi eni o Omo araye esere o Commander Ebenezer Do your best and leave the rest Commander Ebenezer Do your best and leave the rest Ile aiye Fun gbadi eni o Omo araye esere o Ile aiye Fun gbadi eni o Omo araye esere o Rere lo pe Africa ma wuwa rere Omo araye esere o Ile aiye Fun gbadi eni o Omo araye esere o