Ibadan (Juju Yoruba)

by Chief Commander Ebenezer Obey

ogbo Ibadan e dupe o fun ile baba wa Oluyole o e dupe o fun ile baba wa Oke ado e dupe o fun ile baba wa Ororo ile ororo ile Ni baba fun wa kisu omi Ibadan o Ibadan 2x Ibadan ye o Ibadan Ibadan o Ibadan Gbogbo omo Ibadan niwon jo olorire 2x Won ki fipa jaiye Won komi mora Jaiye jaiye oluyole jowo dara Oluyole area titi tofi dorun mu 2x Ajagbe o yewo tiwa Oko funmilayo tiwa Oko iyabo tiwa Baba denrele o tiwa Baba adewale o tiwa Eye aluko gbewe wa wo e o Keto fibadan sere o Mi o ni fibadan sere o Kato fibadan sere yi Ife wa yonu Keto fibadan sere o Mi o ni fibadan sere o Kato fibadan sere yi Ife wa yonu Owo yonu o owo yonu Yi awa yonu Aja ye opo ju wani yi awa yonu