Iba O Messiah Oba

by Chief Commander Ebenezer Obey

Iba o Messiah oba, Mo juba e Laye mi, baba ko ranmi lowo kaye ye mi Laye mi, baba ko ranmi lowo kinu mi dun, kin ma moshi baba, Iba o Messiah oba, mo juba e Mofi towotowo juba re o, Eleduwa oba Oba tiipe koyeni oyigiyigi, oba Edumare, Mofi towotowo juba re o, Eleduwa oba Iba o Messiah oba mojuba e Ngo sunmo Olorun, ngo sunmo o Botilese iponju lomumi wa o, Sibesibe, ngo ma korin sunmo o sunmo Olorun sunmo odo e Iba o Messiah oba mojuba e Awa fijo, awa f'ayo korin soba rere Ayeraye Olorun oun logbe mi leke'danwo gbogbo Awa yo yo nnu ore re, awa yo si lagogo Lagogo e hoo, lagogo eyoo Bi a ba seni loore, ope laada o, o seun, Iba o Messiah oba mojuba e Awa fijo, awa f'ayo korin soba rere Ayeraye Olorun oun logbe mi leke'danwo gbogbo Awa yo yo nnu ore re, awa yo si lagogo Lagogo e hoo, lagogo eyoo Bi a ba seni loore, ope laada o, o seun, Iba o Messiah oba mojuba e Iba o Messiah oba mojuba e Yeo ,Yeo ,Yeo, Ah !Jesu Kristi oba olojo oni o, madoju tiwa o, Ah Jesu Kristi oba Yeo, Yeo, Yeo, Ah! Jesu Kristi oba olojo oni o, madoju tiwa o, Ah Jesu Kristi oba Jesu ni darijiwon o Baba nitori won o mo ohun ti won n se Sugbon ao rira, ao rira, ao tun rari lojo ajinde Iba o Messiah oba mojuba e Yungba,Yungba, yo yo yo A dun joyin lo Aye mi adun adun adun, a dun joyin lo Emi n gbo gbare gbare gbare Maritemi gba, Emi n gbo gbare gbare gbare Ire owo, emi n gbo gbare gbare gbare Ire omo, emi n gbo gbare gbare gbare Ire alaafia, emi n gbo gbare gbare gbare Ayo atidunnu, emi n gbo gbare gbare gbare Mari temi gba, emi n gbo gbare gbare gbare Omo Olorun ko gbodo yodi, Rara o, rara o, rara o, rara oro ti o nilaari ore mi, mee lowo si oro rohun rohun, rederede, jatijati, jagbajagba, oro ti o ni laari ore mi, mee lowo si. Toba n gbo gbare gbare Emi n gbo gbare gbare gbare Mari temi gba, emi n gbo gbare gbare gbare Satan shame unto you ,all powers belong to Jesus, Satan shame unto you o, all powers belong to Jesus ......