Egba (Juju Yoruba)

by Chief Commander Ebenezer Obey

a lomo Abeokuta Ilu rere ilu olola Ibi gbogbo losan nilu wa Egba omo ilu saki Awa lomo Abeokuta Ilu rere ilu olola Ibi gbogbo losan nilu wa Egba omo ilu saki Te ba fe molumo E lo seba folumo Te ba fe molumo E lo seba folumo Teba ti de giga E duro wapa otun e Teba ti de giga E duro wapa otun e Ona wo le o gbe baje oni ke o 2x Egba jaiye ofi tedo si Kawon ni baba 2x Fun awon toku lehin Ema deno deba o Igba eranko yi deno teko Ekun baba eranko Eba mi ki ore mi oko Elizabeth Igba eranko yi deno teko Ekun baba eranko * Igba eranko yi deno teko Ekun baba eranko * Igba eshinshin ni deno teko Lowo baba eshinshin * Igba eshinshin ni deno teko Lowo baba eshinshin * Igba eranko yi deno teko Ekun baba eranko * Igba eshinshin ni deno teko Lowo baba eshinshin