Ajokodabi Ile (Juju/High-Life)

by Chief Commander Ebenezer Obey

ogbo ileku kan tepa mose Gbogbo ileku sa won lo lowo Gbogbo ileku kan tepa mose Gbogbo ileku sa won lo lowo Ijebu omo alare won dara Ijebu omo alare won seniyan Ijebu omo alare won dara Ijebu omo alare won seniyan Kekere ijebu o owo ni owo ni Agba ijebu o owo ni owo ni Eweso o eweso o 2x Ile mise logoje mi gojo sejo Omo alare eweso o Ema bolurawi kema ba jiya Iwa nilayode amasigbodu Olayode omosibodu Awo oke omosibodu Eweso o eweso o 2x Ile mise logoje mi gojo sejo Omo alare eweso o Eweso o eweso o Omo alare ewese o * Eweso o eweso o Omo alare ewese o * Eweso o eweso o Omo alare ewese o