CCC Hymn 731

by Celestial

1: E gbe ori yin si oke e, Ani enyin, enu ona, Ki a si gbe nyin si oke e, Enyin ‘lekun aiyeraiye, Chorus: K’Oba ogo wo inu ile, Wo nu ile Mimo Re wa, Ta ha ni Oba Ogo na? Jehovah ni Oba Ogo Ta ha ni Oba Ogo na? Jesu Kristi Olugbala. 2: E se l’Oba, enyin enia Re, Ki gbogbo araiye se l’Oba, Ki e si ma fi i ayo sin, F’ayo fi sin tokantokan, Chorus: K’Oba ogo wo inu ile, Wo nu ile Mimo Re wa, Ta ha ni Oba Ogo na? Jehovah ni Oba Ogo Ta ha ni Oba Ogo na? Jesu Kristi Olugbala. Agbara Emi Mimo se tan, Lati wa gunwa ninu wa, E fi okan mimo ke pe e, Ke pe ninu ‘le Mimo Re, Chorus: K’Oba ogo wo inu ile, Wo nu ile Mimo Re wa, Ta ha ni Oba Ogo na? Jehovah ni Oba Ogo Ta ha ni Oba Ogo na? Jesu Kristi Olugbala. 4: E fi iwa mimo ati ife, Sin Oba wa ‘rinu rode, Olumoran okan araiye, Yio si gbo ohu8n igbe wa, Chorus: K’Oba ogo wo inu ile, Wo nu ile Mimo Re wa, Ta ha ni Oba Ogo na? Jehovah ni Oba Ogo Ta ha ni Oba Ogo na? Jesu Kristi Olugbala. Amin