CCC Hymn 713

by Celestial Hymn

1: B’agogo Orun balu, Awa omo Ijo Mimo, A o duro, a o duro, Niwaju Re, Niwaju Re, Chorus: A o duro, niwaju Re, A o b’awon Angeli korin, Ogo, ogo f’Oba wa, Halleluya, Halleluya, A o duro o, niwaju Re. Ijo Mimo e mura, E damure nyin giri, Nitori, nitori Bi Jesu bade, aw o duro, Chorus: A o duro, niwaju Re, A o b’awon Angeli korin, Ogo, ogo f’Oba wa, Halleluya, Halleluya, A o duro o, niwaju Re. Amin