CCC Hymn 620
by Celeatial
1: Enyin omo Ijo Mimo,
E damure nyin giri,
Ka si le b’awon Angeli,
Ka Alleluya lojo na,
Ka si le bo sinu ayo Oluwa,
Solo: Damuso – fun Baba,
Awamaridi jinle Kabiyesi,
Jehovah Mimo jowo,
Ma se le mi lodo Re,
Nipa ore ofe Re,
Ki nle de be.
2: Nitori Jesu mbo wa,
Lati se ‘dajo aiye,
Yio si kawon ayanfe,
Lo sodo Baba loke,
A o si b’awon Angeli k’Alleluya,
Solo: Damuso – fun Baba,
Awamaridi jinle Kabiyesi,
Jehovah Mimo jowo,
Ma se le mi lodo Re,
Nipa ore ofe Re,
Ki nle de be.
3: Jesu si npada bo wa,
Gege bi ole loru,
Enyin ayanfe Oluwa,
E je ka mura sile,
Lati le b’awon Angeli,
Fo lo sorun,
Solo: Damuso – fun Baba,
Awamaridi jinle Kabiyesi,
Jehovah Mimo jowo,
Ma se le mi lodo Re,
Nipa ore ofe Re,
Ki nle de be. Amin