CCC hymn 580
by Celestial
1: Nigbati fere Oluwa yio dun,
Ti ise ki o si mo,
A o pe ohun alaye ‘gun merin wa,
Lati fi ise won han,
Ni’waju Olugbala wa,
Nigbati fere yio dun, emi o wa nibe,
Chorus: Nigbati, fere yio dun, lohun,
Nigbati, fere yio dun, lohun,
Nigbati, fere yio dun, lohun,
Nigbati, fere yio dun,
Emi yio wa nibe.
2: Awa yio ma korin,
Lati owuro ti yi dale,
Awa yio ma f’ogo fun Olorun,
Olugbala yio ma pe gbogbo wa ni omo
rere,
Chorus: Nigbati, fere yio dun, lohun,
Nigbati, fere yio dun, lohun,
Nigbati, fere yio dun, lohun,
Nigbati, fere yio dun,
Emi yio wa nibe. Amin