CCC Hymn 58

by Celestial Hymn

E korin, k’e gborin soke S’Oba Oluwa mi, K’Oba Mimo ko gba wa la Ninu Ijo Mimo yi, K’Oba Mimo, ko gba wa la Ko fun wa laranse, Kopa wa mo kuro ninu ese, Ko wa dariji wa Amin