CCC Hymn 544
by Celestial Hymn
E je ka dipo Jesu Kristi mu,
Ka mokan kuro ninu aniyan,
Aiye ti yio fo lo,
Solo: Kale ri gbala,
Chorus: Gbeke re le, gbeke le ‘fe Re,
Gbeke re le, gboju re soke,
Gbeke re le gboju re soke,
Gbeke re le dan anu Re wo,
Sa gbeke re le Jesu. Amin