CCC Hymn 537

by Celestial Hymn

1: Ma foya ni apa Jesu, Ko si ohun eru kan, Ina ti njo ko le sunmo o, Ogun esu ti di wiwo mole. 2: Mo ro mo agbelebu Re, Mo ka ohun gbogbo sa san, Ma beru ire okan mi, Ayo mbe ninu eje Jesu. 3: Emi ko ni ju O sile, Jesu Olugbala mi, Ninu Re ni iye mi wa, Ire ni Olugbala mi. 4: Ijo Mimo bu si ayo, Oko iyawo wa pelu Re, Ayo ni tire si ma yo, Ade iye na yio je tire. Amin