CCC Hymn 529
by Celestial Hymn
Gbeke re le Oluwa ninu Ijo Mimo yi,
Gbeke re le Oluwa ninu Ijo Mimo yi,
Ijo Mimo nla kan ni,
Nibiti Kristi wa a,
Okan mi nfe nigbagbogbo,
Lati ba Oluwa gbe,
Okan mi nfe nigbagbogbo,
Lati ba Oluwa gbe. Amin
by Celestial Hymn